قَالَ
هَلۡ
ءَامَنُكُمۡ
عَلَيۡهِ
إِلَّا
كَمَآ
أَمِنتُكُمۡ
عَلَىٰٓ
أَخِيهِ
مِن
قَبۡلُ
فَٱللَّهُ
خَيۡرٌ
حَٰفِظٗاۖ
وَهُوَ
أَرۡحَمُ
ٱلرَّٰحِمِينَ
٦٤
Ó sọ pé: “Ṣé kí n̄g gbà yín gbọ́ lórí rẹ̀ bí kò ṣe bí mó ṣe gbà yín gbọ́ ní ìṣaájú lórí ọmọ-ìyá rẹ̀? Nítorí náà, Allāhu lóore jùlọ ní Olùṣọ́. Òun sì ni Aláàánú-jùlọ nínú àwọn aláàánú.”
Read Tafsir
Ibn Kathir (Abridged)
Yusuf's Brothers ask Ya`qub's Permission to send Their Brother Binyamin with Them to Egypt
Allah says that when they went back to their father,
قَالُواْ يأَبَانَا مُنِعَ مِنَّا الْكَيْلُ
(they said: "O our father! No more measure of grain shall we get...") `after this time, unless you send our brother
…Yusuf's Brothers ask Ya`qub's Permission to send Their Brother Binyamin with Them to Egypt
Allah says that when they went back to their father,
قَالُوا
…