وَقَالَ
ٱلَّذِينَ
كَفَرُواْ
لِرُسُلِهِمۡ
لَنُخۡرِجَنَّكُم
مِّنۡ
أَرۡضِنَآ
أَوۡ
لَتَعُودُنَّ
فِي
مِلَّتِنَاۖ
فَأَوۡحَىٰٓ
إِلَيۡهِمۡ
رَبُّهُمۡ
لَنُهۡلِكَنَّ
ٱلظَّٰلِمِينَ
١٣
Àwọn tó ṣàì gbàgbọ́ wí fún àwọn Òjíṣẹ́ wọn pé: “Dájúdájú àwa yóò le yín jáde kúrò lórí ilẹ̀ wa tàbí kí ẹ kúkú padà sínú ẹ̀sìn wa.” Nígbà náà, Olúwa wọn fi ìmísí ránṣẹ́ sí wọn pé: “Dájúdájú A máa pa àwọn alábòsí run.
Read q-and-a.tafsir
Ibn Kathir (Abridged)
Disbelieving Nations threaten Their Messengers with Expulsion
Allah narrates to us how the disbelieving nations threatened their Messengers, that being, expulsion from their land and banshiment. For instance, the people of Prophet Shu`ayb, peace be upon him, said to him and to those who believed in h
…Disbelieving Nations threaten Their Messengers with Expulsion
Allah narrates to us how the disbelieving nations threatened their Messengers, that being
…