وَلَكُمۡ
فِيهَا
مَنَٰفِعُ
وَلِتَبۡلُغُواْ
عَلَيۡهَا
حَاجَةٗ
فِي
صُدُورِكُمۡ
وَعَلَيۡهَا
وَعَلَى
ٱلۡفُلۡكِ
تُحۡمَلُونَ
٨٠
Àwọn àǹfààní (mìíràn) wà fún yín lára ẹran-ọ̀sìn. Àti nítorí kí ẹ lè dé ọ̀nà jíjìn tó wà lọ́kàn yín lórí (gígùn) wọ́n (kiri). Ẹ sì ń fi àwọn (ẹran-ọ̀sìn) àti ọkọ̀ ojú-omi gbé àwọn ẹrù.
Read q-and-a.tafsir
Ibn Kathir (Abridged)
The Cattle are also a Blessing from Allah and a Sign from Him
Allah reminds His servants of His blessing in that He created the cattle Al-An`am for them, which refers to camels, cows and sheep; some of them they ride and some of them they eat. Camels may be ridden or eaten; their milk is drunk and th
…The Cattle are also a Blessing from Allah and a Sign from Him
Allah reminds His servants of His blessing in that He created the cattle Al-An`am for the
…