Iniciar sesión
Iniciar sesión
Iniciar sesión
Seleccionar idioma

An-Náyam 53:17 ما زاغ البصر وما طغى ١٧

Página 526 · Juz 27

مَا
زَاغَ
ٱلۡبَصَرُ
وَمَا
طَغَىٰ
١٧
Ojú (Ànábì) kò yẹ̀, kò sì tayọ ẹnu-ààlà.
Continuar leyendo

Lee Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

The Trustworthy Angel brought Allah's Revelation to the Trustworthy Messenger

Allah the Exalted states that the Message His servant and Messenger Muhammad ﷺ brought to people was taught to him by,

شَدِيدُ الْقُوَى

(mighty in power), he is Jibril, peace be upon him,

إِنَّهُ لَقَوْلُ رَسُولٍ كَرِيمٍ ذ

…

The Trustworthy Angel brought Allah's Revelation to the Trustworthy Messenger

Allah the Exalted states that the Message His servant and Messenger Muha

…
Ver Tafsires

Leer en contexto

1. Allāhu fi gbólóhùn kọ̀ọ̀kan nínú al-Ƙur’ān alápọ̀n-ọ́nlé nígbà tí ó bá sọ̀kalẹ̀ láti ojú sánmọ̀ búra. 2. Ẹni yín kò ṣìnà, kò sì sọnù. 3. Àti pé kò níí sọ̀rọ̀ ìfẹ́-inú. 4. Kò níí sọ ohun kan tayọ ìmísí tí A fi ránṣẹ́ sí i. 5. Alágbára (ìyẹn, mọlāika Jibrīl) l’ó kọ́ ọ ní ìmọ̀ (al-Ƙur’ān). 6. Ó ní àlàáfíà tó péye, ó sì dúró wámúwámú, 7. nígbà tí ó wà nínú òfurufú lókè pátápátá. 8. Lẹ́yìn náà, ó sún mọ́ (Ànábì - kí ìkẹ́ àti ọlà Allāhu máa bá a -). Ó sì sọ̀kalẹ̀ (tọ̀ ọ́ wá). 9. (Àlàfo ààrin àwọn méjèèjì) sì tó ìwọ̀n ọrún ọfà méjì, tàbí kí ó kéré (sí ìyẹn). 10. Allāhu sì fún ẹrúsìn Rẹ̀ ní ìmísí tó fún un. 11. Ọkàn (Ànábì - kí ìkẹ́ àti ọlà Allāhu máa bá a -) kò parọ́ ohun tó rí. 12. Ṣé ẹ óò jà á níyàn nípa ohun tó rí ni? 13. Àti pé dájúdájú ó tún rí i nígbà kejì 14. níbi igi sidirah al-Muntahā, 15. nítòsí rẹ̀ ni Ọgbà Ibùgbé (gbére) wà. 16. (Rántí) nígbà tí ohun tó bo igi Sidirah bò ó mọ́lẹ̀. 17. Ojú (Ànábì) kò yẹ̀, kò sì tayọ ẹnu-ààlà. 18. Dájúdájú ó rí nínú àwọn àmì Olúwa rẹ̀, tó tóbi.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Continuar leyendo

Notas y reflexiones

No tienes ninguna nota ni reflexión sobre este versículo.

Notes placeholders

Mantente conectado al Corán ❤️

Breves recordatorios significativos para reconectar, reflexionar y mantenerse conectado con el Corán.

Lea, escuche, busque y reflexione sobre el Corán

Quran.com es una plataforma confiable utilizada por millones de personas en todo el mundo para leer, buscar, escuchar y reflexionar sobre el Corán en varios idiomas. Ofrece traducciones, tafsir, recitaciones, traducción palabra por palabra y herramientas para un estudio más profundo, haciendo que el Corán sea accesible para todos.

Como Sadaqah Jariyah, Quran.com se dedica a ayudar a las personas a conectar profundamente con el Corán. Con el apoyo de Quran.Foundation , una organización sin fines de lucro 501(c)(3), Quran.com continúa creciendo como un recurso gratuito y valioso para todos, Alhamdulillah.

Navegar
Inicio
Radio Coránica
Recitadores
Sobre nosotros
Desarrolladores
Actualizaciones de productos
Retroalimentación
Ayuda
Donar
Nuestros Proyectos
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Proyectos sin fines de lucro adquiridos, administrados o patrocinados por Quran.Foundation
Enlaces populares
Súplicas del Corán
Versículo del Corán del día
Ayatul Kursi
Yasin
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqiah
Al-Kahf
Al Muzzammil
Mapa del sitio webPrivacidadTérminos y condiciones
© 2026 Quran.com. Reservados todos los derechos
Contribuir