Sign in
Sign in
Sign in
Select Language

78. Surah An-Naba, Yoruba Translation

The Tidings

Read the complete Surah An-Naba with its Yoruba translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni.

Info
In the Name of Allah—the Most Compassionate, Most Merciful
78:1
عم يتساءلون ١
عَمَّ يَتَسَآءَلُونَ ١
عَمَّ
يَتَسَآءَلُونَ
١
Nípa kí ni wọ́n ń bíra wọn léèrè ná?
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:2
عن النبا العظيم ٢
عَنِ ٱلنَّبَإِ ٱلْعَظِيمِ ٢
عَنِ
ٱلنَّبَإِ
ٱلۡعَظِيمِ
٢
Nípa ìró ìkọ̀kọ̀ ńlá ni,
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:3
الذي هم فيه مختلفون ٣
ٱلَّذِى هُمْ فِيهِ مُخْتَلِفُونَ ٣
ٱلَّذِي
هُمۡ
فِيهِ
مُخۡتَلِفُونَ
٣
èyí tí wọ́n ń yapa-ẹnu lórí rẹ̀.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:4
كلا سيعلمون ٤
كَلَّا سَيَعْلَمُونَ ٤
كـَلَّا
سَيَعۡلَمُونَ
٤
Rárá! Wọ́n ń bọ̀ wá mọ̀.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:5
ثم كلا سيعلمون ٥
ثُمَّ كَلَّا سَيَعْلَمُونَ ٥
ثُمَّ
كـَلَّا
سَيَعۡلَمُونَ
٥
Lẹ́yìn náà, rárá sẹ́, wọ́n ń bọ̀ wá mọ̀.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:6
الم نجعل الارض مهادا ٦
أَلَمْ نَجْعَلِ ٱلْأَرْضَ مِهَـٰدًۭا ٦
أَلَمۡ
نَجۡعَلِ
ٱلۡأَرۡضَ
مِهَٰدٗا
٦
Ǹjẹ́ Àwa kò ṣe ilẹ̀ ní ìtẹ́ bí,
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:7
والجبال اوتادا ٧
وَٱلْجِبَالَ أَوْتَادًۭا ٧
وَٱلۡجِبَالَ
أَوۡتَادٗا
٧
àti àwọn àpáta ní èèkàn (fún ilẹ̀)?
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:8
وخلقناكم ازواجا ٨
وَخَلَقْنَـٰكُمْ أَزْوَٰجًۭا ٨
وَخَلَقۡنَٰكُمۡ
أَزۡوَٰجٗا
٨
A sì ṣẹ̀dá yín ní oríṣiríṣi (akọ àti abo).
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:9
وجعلنا نومكم سباتا ٩
وَجَعَلْنَا نَوْمَكُمْ سُبَاتًۭا ٩
وَجَعَلۡنَا
نَوۡمَكُمۡ
سُبَاتٗا
٩
A ṣe oorun yín ní ìsinmi.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:10
وجعلنا الليل لباسا ١٠
وَجَعَلْنَا ٱلَّيْلَ لِبَاسًۭا ١٠
وَجَعَلۡنَا
ٱلَّيۡلَ
لِبَاسٗا
١٠
A tún ṣe alẹ́ ní ìbora.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:11
وجعلنا النهار معاشا ١١
وَجَعَلْنَا ٱلنَّهَارَ مَعَاشًۭا ١١
وَجَعَلۡنَا
ٱلنَّهَارَ
مَعَاشٗا
١١
A tún ṣe ọ̀sán ní (àsìkò fún) wíwá ìjẹ-ìmu.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:12
وبنينا فوقكم سبعا شدادا ١٢
وَبَنَيْنَا فَوْقَكُمْ سَبْعًۭا شِدَادًۭا ١٢
وَبَنَيۡنَا
فَوۡقَكُمۡ
سَبۡعٗا
شِدَادٗا
١٢
A tún mọ sánmọ̀ méje tó lágbára sókè yín.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:13
وجعلنا سراجا وهاجا ١٣
وَجَعَلْنَا سِرَاجًۭا وَهَّاجًۭا ١٣
وَجَعَلۡنَا
سِرَاجٗا
وَهَّاجٗا
١٣
A tún ṣe òòrùn ní ìmọ́lẹ̀ tó ń tàn gbòlà.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:14
وانزلنا من المعصرات ماء ثجاجا ١٤
وَأَنزَلْنَا مِنَ ٱلْمُعْصِرَٰتِ مَآءًۭ ثَجَّاجًۭا ١٤
وَأَنزَلۡنَا
مِنَ
ٱلۡمُعۡصِرَٰتِ
مَآءٗ
ثَجَّاجٗا
١٤
Àti pé A sọ omi tó ń bọ́ tẹ̀léra wọn kalẹ̀ láti inú àwọn ẹ̀ṣújò
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:15
لنخرج به حبا ونباتا ١٥
لِّنُخْرِجَ بِهِۦ حَبًّۭا وَنَبَاتًۭا ١٥
لِّنُخۡرِجَ
بِهِۦ
حَبّٗا
وَنَبَاتٗا
١٥
nítorí kí Á lè fi mú kóró èso àti irúgbìn jáde
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:16
وجنات الفافا ١٦
وَجَنَّـٰتٍ أَلْفَافًا ١٦
وَجَنَّٰتٍ
أَلۡفَافًا
١٦
pẹ̀lú àwọn ọgbà tó kún digbí fún n̄ǹkan oko.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:17
ان يوم الفصل كان ميقاتا ١٧
إِنَّ يَوْمَ ٱلْفَصْلِ كَانَ مِيقَـٰتًۭا ١٧
إِنَّ
يَوۡمَ
ٱلۡفَصۡلِ
كَانَ
مِيقَٰتٗا
١٧
Dájúdájú ọjọ́ ìpínyà, ó ní gbèdéke àkókò kan.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:18
يوم ينفخ في الصور فتاتون افواجا ١٨
يَوْمَ يُنفَخُ فِى ٱلصُّورِ فَتَأْتُونَ أَفْوَاجًۭا ١٨
يَوۡمَ
يُنفَخُ
فِي
ٱلصُّورِ
فَتَأۡتُونَ
أَفۡوَاجٗا
١٨
(Ìyẹn ni) ọjọ́ tí wọ́n á fọn fèrè oníwo fún àjíǹde. Ẹ̀yin yó sì máa wá níjọ-níjọ.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:19
وفتحت السماء فكانت ابوابا ١٩
وَفُتِحَتِ ٱلسَّمَآءُ فَكَانَتْ أَبْوَٰبًۭا ١٩
وَفُتِحَتِ
ٱلسَّمَآءُ
فَكَانَتۡ
أَبۡوَٰبٗا
١٩
Wọ́n sì máa ṣí sánmọ̀ sílẹ̀. Ó sì máa di àwọn ìlẹ̀kùn.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:20
وسيرت الجبال فكانت سرابا ٢٠
وَسُيِّرَتِ ٱلْجِبَالُ فَكَانَتْ سَرَابًا ٢٠
وَسُيِّرَتِ
ٱلۡجِبَالُ
فَكَانَتۡ
سَرَابًا
٢٠
Wọ́n máa mú àwọn àpáta rìn (bọ́ sí àyè mìíràn). Ó sì máa di ahúnpeéná.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:21
ان جهنم كانت مرصادا ٢١
إِنَّ جَهَنَّمَ كَانَتْ مِرْصَادًۭا ٢١
إِنَّ
جَهَنَّمَ
كَانَتۡ
مِرۡصَادٗا
٢١
Dájúdájú iná Jahanamọ, ó lúgọ sílẹ̀ lójú ọ̀nà.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:22
للطاغين مابا ٢٢
لِّلطَّـٰغِينَ مَـَٔابًۭا ٢٢
لِّلطَّٰغِينَ
مَـَٔابٗا
٢٢
(Ó jẹ́) ibùgbé fún àwọn alákọyọ.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:23
لابثين فيها احقابا ٢٣
لَّـٰبِثِينَ فِيهَآ أَحْقَابًۭا ٢٣
لَّٰبِثِينَ
فِيهَآ
أَحۡقَابٗا
٢٣
Wọn yóò máa gbé inú rẹ̀ fún ìgbà gbọọrọ.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:24
لا يذوقون فيها بردا ولا شرابا ٢٤
لَّا يَذُوقُونَ فِيهَا بَرْدًۭا وَلَا شَرَابًا ٢٤
لَّا
يَذُوقُونَ
فِيهَا
بَرۡدٗا
وَلَا
شَرَابًا
٢٤
Wọn kò níí rí ìtura tàbí ohun mímu kan tọ́wò nínú rẹ̀,
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:25
الا حميما وغساقا ٢٥
إِلَّا حَمِيمًۭا وَغَسَّاقًۭا ٢٥
إِلَّا
حَمِيمٗا
وَغَسَّاقٗا
٢٥
àyàfi omi tó gbóná parí àti àwọnúwẹ̀jẹ̀.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:26
جزاء وفاقا ٢٦
جَزَآءًۭ وِفَاقًا ٢٦
جَزَآءٗ
وِفَاقًا
٢٦
(Ó jẹ́) ẹ̀san tó ṣe wẹ́kú (iṣẹ́ wọn).
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:27
انهم كانوا لا يرجون حسابا ٢٧
إِنَّهُمْ كَانُوا۟ لَا يَرْجُونَ حِسَابًۭا ٢٧
إِنَّهُمۡ
كَانُواْ
لَا
يَرۡجُونَ
حِسَابٗا
٢٧
Dájúdájú wọn kì í retí ìṣírò-iṣẹ́.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:28
وكذبوا باياتنا كذابا ٢٨
وَكَذَّبُوا۟ بِـَٔايَـٰتِنَا كِذَّابًۭا ٢٨
وَكَذَّبُواْ
بِـَٔايَٰتِنَا
كِذَّابٗا
٢٨
Wọ́n sì pe àwọn āyah Wa ní irọ́ gan-an.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:29
وكل شيء احصيناه كتابا ٢٩
وَكُلَّ شَىْءٍ أَحْصَيْنَـٰهُ كِتَـٰبًۭا ٢٩
وَكُلَّ
شَيۡءٍ
أَحۡصَيۡنَٰهُ
كِتَٰبٗا
٢٩
Gbogbo n̄ǹkan sì ni A ti ṣe àkọsílẹ̀ rẹ̀ sínú Tírà kan.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:30
فذوقوا فلن نزيدكم الا عذابا ٣٠
فَذُوقُوا۟ فَلَن نَّزِيدَكُمْ إِلَّا عَذَابًا ٣٠
فَذُوقُواْ
فَلَن
نَّزِيدَكُمۡ
إِلَّا
عَذَابًا
٣٠
Nítorí náà, ẹ tọ́ (ìyà) wò. A ò sì níí ṣe àlékún kan fún yín bí kò ṣe ìyà.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:31
ان للمتقين مفازا ٣١
إِنَّ لِلْمُتَّقِينَ مَفَازًا ٣١
إِنَّ
لِلۡمُتَّقِينَ
مَفَازًا
٣١
Dájúdájú ìgbàlà wà fún àwọn olùbẹ̀rù (Allāhu).
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:32
حدايق واعنابا ٣٢
حَدَآئِقَ وَأَعْنَـٰبًۭا ٣٢
حَدَآئِقَ
وَأَعۡنَٰبٗا
٣٢
Àwọn ọgbà oko àti èso àjàrà,
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:33
وكواعب اترابا ٣٣
وَكَوَاعِبَ أَتْرَابًۭا ٣٣
وَكَوَاعِبَ
أَتۡرَابٗا
٣٣
àti àwọn ọlọ́mọge, tí wọn kò júra wọn lọ lọ́jọ́-orí,
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:34
وكاسا دهاقا ٣٤
وَكَأْسًۭا دِهَاقًۭا ٣٤
وَكَأۡسٗا
دِهَاقٗا
٣٤
àti ife ọtí tó kún dẹnu (ni ẹ̀san wọn).
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:35
لا يسمعون فيها لغوا ولا كذابا ٣٥
لَّا يَسْمَعُونَ فِيهَا لَغْوًۭا وَلَا كِذَّٰبًۭا ٣٥
لَّا
يَسۡمَعُونَ
فِيهَا
لَغۡوٗا
وَلَا
كِذَّٰبٗا
٣٥
Wọn kò níí gbọ́ ìsọkúsọ àti ọ̀rọ̀ irọ́ nínú rẹ̀.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:36
جزاء من ربك عطاء حسابا ٣٦
جَزَآءًۭ مِّن رَّبِّكَ عَطَآءً حِسَابًۭا ٣٦
جَزَآءٗ
مِّن
رَّبِّكَ
عَطَآءً
حِسَابٗا
٣٦
(Ó jẹ́) ẹ̀san láti ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ, (ó sì jẹ́) ọrẹ ní ìbámu sí ìṣírò-iṣẹ́ (wọn).
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:37
رب السماوات والارض وما بينهما الرحمان لا يملكون منه خطابا ٣٧
رَّبِّ ٱلسَّمَـٰوَٰتِ وَٱلْأَرْضِ وَمَا بَيْنَهُمَا ٱلرَّحْمَـٰنِ ۖ لَا يَمْلِكُونَ مِنْهُ خِطَابًۭا ٣٧
رَّبِّ
ٱلسَّمَٰوَٰتِ
وَٱلۡأَرۡضِ
وَمَا
بَيۡنَهُمَا
ٱلرَّحۡمَٰنِۖ
لَا
يَمۡلِكُونَ
مِنۡهُ
خِطَابٗا
٣٧
(Ẹsan náà wá láti ọ̀dọ̀) Olúwa àwọn sánmọ̀, ilẹ̀ àti ohun tó wà láààrin méjèèjì, Àjọkẹ́-ayé. Wọn kò sì ní ìkápá ọ̀rọ̀ lọ́dọ̀ Rẹ̀.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:38
يوم يقوم الروح والملايكة صفا لا يتكلمون الا من اذن له الرحمان وقال صوابا ٣٨
يَوْمَ يَقُومُ ٱلرُّوحُ وَٱلْمَلَـٰٓئِكَةُ صَفًّۭا ۖ لَّا يَتَكَلَّمُونَ إِلَّا مَنْ أَذِنَ لَهُ ٱلرَّحْمَـٰنُ وَقَالَ صَوَابًۭا ٣٨
يَوۡمَ
يَقُومُ
ٱلرُّوحُ
وَٱلۡمَلَٰٓئِكَةُ
صَفّٗاۖ
لَّا
يَتَكَلَّمُونَ
إِلَّا
مَنۡ
أَذِنَ
لَهُ
ٱلرَّحۡمَٰنُ
وَقَالَ
صَوَابٗا
٣٨
Ọjọ́ tí mọlāika Jibrīl àti àwọn mọlāika (mìíràn) yóò dúró ní ọ̀wọ̀ọ̀wọ́. Wọn kò sì níí sọ̀rọ̀ àfi ẹni tí Àjọké-ayé bá yọ̀ǹda fún. Onítọ̀ún sì máa sọ̀rọ̀ tó máa ṣe wẹ́kú.
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:39
ذالك اليوم الحق فمن شاء اتخذ الى ربه مابا ٣٩
ذَٰلِكَ ٱلْيَوْمُ ٱلْحَقُّ ۖ فَمَن شَآءَ ٱتَّخَذَ إِلَىٰ رَبِّهِۦ مَـَٔابًا ٣٩
ذَٰلِكَ
ٱلۡيَوۡمُ
ٱلۡحَقُّۖ
فَمَن
شَآءَ
ٱتَّخَذَ
إِلَىٰ
رَبِّهِۦ
مَـَٔابًا
٣٩
Ìyẹn ni ọjọ́ òdodo. Nítorí náà, ẹni tí ó bá fẹ́ kí ó mú ọ̀nà tó máa gbà ṣẹ́rí padà sí ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ̀ pọ̀n (ní ti ìronúpìwàdà).
Tafsirs
Lessons
Reflections
78:40
انا انذرناكم عذابا قريبا يوم ينظر المرء ما قدمت يداه ويقول الكافر يا ليتني كنت ترابا ٤٠
إِنَّآ أَنذَرْنَـٰكُمْ عَذَابًۭا قَرِيبًۭا يَوْمَ يَنظُرُ ٱلْمَرْءُ مَا قَدَّمَتْ يَدَاهُ وَيَقُولُ ٱلْكَافِرُ يَـٰلَيْتَنِى كُنتُ تُرَٰبًۢا ٤٠
إِنَّآ
أَنذَرۡنَٰكُمۡ
عَذَابٗا
قَرِيبٗا
يَوۡمَ
يَنظُرُ
ٱلۡمَرۡءُ
مَا
قَدَّمَتۡ
يَدَاهُ
وَيَقُولُ
ٱلۡكَافِرُ
يَٰلَيۡتَنِي
كُنتُ
تُرَٰبَۢا
٤٠
Dájúdájú A fi ìyà tó súnmọ́ ṣe ìkìlọ̀ fún yín. Ọjọ́ tí ènìyàn yóò máa wo ohun tí ó tì síwájú, aláìgbàgbọ́ yó sì wí pé: “Yéè, èmi ìbá sì jẹ́ erùpẹ̀, (èmi ìbá là nínú ìyà).”
Tafsirs
Lessons
Reflections

End of Chapter

Next Surah: An-Nazi'atTafsir of Surah An-Naba
Read More
79. An-Nazi'atThose who drag forth
Next
77. Al-MursalatThe Emissaries
Previous
ExploreMy Quran

Achieve Your Quran Goals

Track Streaks, Create Custom Goals,
Stay Consistent

Set a Custom Goal
Next Surah: An-Nazi'atTafsir of Surah An-Naba

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran Space
Quran.ai
Quran Audio
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute