Sign in
Sign in
Sign in
Select Language

79. Surah An-Nazi'at, Yoruba Translation

Those who drag forth

Read the complete Surah An-Nazi'at with its Yoruba translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni.

Info
In the Name of Allah—the Most Compassionate, Most Merciful
79:1
والنازعات غرقا ١
وَٱلنَّـٰزِعَـٰتِ غَرْقًۭا ١
وَٱلنَّٰزِعَٰتِ
غَرۡقٗا
١
Allāhu fi àwọn mọlāika tó ń fi ọ̀nà èle gba ẹ̀mí àwọn aláìgbàgbọ́ búra.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:2
والناشطات نشطا ٢
وَٱلنَّـٰشِطَـٰتِ نَشْطًۭا ٢
وَٱلنَّٰشِطَٰتِ
نَشۡطٗا
٢
Ó tún fi àwọn mọlāika tó ń fi ọ̀nà ẹ̀rọ̀ gba ẹ̀mí àwọn onígbàgbọ́ òdodo búra.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:3
والسابحات سبحا ٣
وَٱلسَّـٰبِحَـٰتِ سَبْحًۭا ٣
وَٱلسَّٰبِحَٰتِ
سَبۡحٗا
٣
Ó tún fi àwọn mọlāika tó ń yára gágá níbi àṣẹ Rẹ̀ búra.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:4
فالسابقات سبقا ٤
فَٱلسَّـٰبِقَـٰتِ سَبْقًۭا ٤
فَٱلسَّٰبِقَٰتِ
سَبۡقٗا
٤
Ó tún fi àwọn mọlāika tó máa ṣíwájú ẹ̀mí àwọn onígbàgbọ́ òdodo wọnú Ọgbà Ìdẹ̀ra tààrà búra.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:5
فالمدبرات امرا ٥
فَٱلْمُدَبِّرَٰتِ أَمْرًۭا ٥
فَٱلۡمُدَبِّرَٰتِ
أَمۡرٗا
٥
Ó tún fi àwọn mọlāika tó ń ṣètò nínú sánmọ̀ àti ilé ayé pẹ̀lú àṣẹ Allāhu búra.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:6
يوم ترجف الراجفة ٦
يَوْمَ تَرْجُفُ ٱلرَّاجِفَةُ ٦
يَوۡمَ
تَرۡجُفُ
ٱلرَّاجِفَةُ
٦
Ní ọjọ́ tí ìmìtìtì máa mi gbogbo ayé tìtì.1
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:7
تتبعها الرادفة ٧
تَتْبَعُهَا ٱلرَّادِفَةُ ٧
تَتۡبَعُهَا
ٱلرَّادِفَةُ
٧
Ohun tí ó máa tẹ̀lé e máa ṣẹlẹ̀ tẹ̀lé e.1
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:8
قلوب يوميذ واجفة ٨
قُلُوبٌۭ يَوْمَئِذٍۢ وَاجِفَةٌ ٨
قُلُوبٞ
يَوۡمَئِذٖ
وَاجِفَةٌ
٨
Àwọn ọkàn yóò máa gbọ̀n pẹ̀pẹ̀ ní ọjọ́ yẹn.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:9
ابصارها خاشعة ٩
أَبْصَـٰرُهَا خَـٰشِعَةٌۭ ٩
أَبۡصَٰرُهَا
خَٰشِعَةٞ
٩
Ojú wọn yó sì wálẹ̀ ní ti ìyẹpẹrẹ.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:10
يقولون اانا لمردودون في الحافرة ١٠
يَقُولُونَ أَءِنَّا لَمَرْدُودُونَ فِى ٱلْحَافِرَةِ ١٠
يَقُولُونَ
أَءِنَّا
لَمَرۡدُودُونَ
فِي
ٱلۡحَافِرَةِ
١٠
Wọn yóò wí pé: “Ṣé Wọ́n tún máa dá wa padà sí ìbẹ̀rẹ̀ ìṣẹ̀mí (bíi tayé ni)?
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:11
ااذا كنا عظاما نخرة ١١
أَءِذَا كُنَّا عِظَـٰمًۭا نَّخِرَةًۭ ١١
أَءِذَا
كُنَّا
عِظَٰمٗا
نَّخِرَةٗ
١١
Ṣé nígbà tí a ti di eegun tó kẹfun tán?”
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:12
قالوا تلك اذا كرة خاسرة ١٢
قَالُوا۟ تِلْكَ إِذًۭا كَرَّةٌ خَاسِرَةٌۭ ١٢
قَالُواْ
تِلۡكَ
إِذٗا
كَرَّةٌ
خَاسِرَةٞ
١٢
Wọ́n wí pé: “Ìdápadà òfò nìyẹn nígbà náà (fún ẹni tó pè é ní irọ́.)”
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:13
فانما هي زجرة واحدة ١٣
فَإِنَّمَا هِىَ زَجْرَةٌۭ وَٰحِدَةٌۭ ١٣
فَإِنَّمَا
هِيَ
زَجۡرَةٞ
وَٰحِدَةٞ
١٣
Nítorí náà, igbe ẹyọ kan sì ni.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:14
فاذا هم بالساهرة ١٤
فَإِذَا هُم بِٱلسَّاهِرَةِ ١٤
فَإِذَا
هُم
بِٱلسَّاهِرَةِ
١٤
Nígbà náà ni wọn yóò bára wọn lórí ilẹ̀ gban̄sasa.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:15
هل اتاك حديث موسى ١٥
هَلْ أَتَىٰكَ حَدِيثُ مُوسَىٰٓ ١٥
هَلۡ
أَتَىٰكَ
حَدِيثُ
مُوسَىٰٓ
١٥
Ǹjẹ́ ọ̀rọ̀ (Ànábì) Mūsā ti dé ọ̀dọ̀ rẹ?
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:16
اذ ناداه ربه بالواد المقدس طوى ١٦
إِذْ نَادَىٰهُ رَبُّهُۥ بِٱلْوَادِ ٱلْمُقَدَّسِ طُوًى ١٦
إِذۡ
نَادَىٰهُ
رَبُّهُۥ
بِٱلۡوَادِ
ٱلۡمُقَدَّسِ
طُوًى
١٦
(Rántí) nígbà tí Olúwa rẹ̀ pè é ní àfonúfojì mímọ́, Tuwā.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:17
اذهب الى فرعون انه طغى ١٧
ٱذْهَبْ إِلَىٰ فِرْعَوْنَ إِنَّهُۥ طَغَىٰ ١٧
ٱذۡهَبۡ
إِلَىٰ
فِرۡعَوۡنَ
إِنَّهُۥ
طَغَىٰ
١٧
Lọ bá Fir‘aon, dájúdájú ó ti tayọ ẹnu-ààlà.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:18
فقل هل لك الى ان تزكى ١٨
فَقُلْ هَل لَّكَ إِلَىٰٓ أَن تَزَكَّىٰ ١٨
فَقُلۡ
هَل
لَّكَ
إِلَىٰٓ
أَن
تَزَكَّىٰ
١٨
Kí o sì sọ pé: “Ǹjẹ o máa ṣàfọ̀mọ́ ara rẹ (kúrò nínú àìgbàgbọ́) bí?
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:19
واهديك الى ربك فتخشى ١٩
وَأَهْدِيَكَ إِلَىٰ رَبِّكَ فَتَخْشَىٰ ١٩
وَأَهۡدِيَكَ
إِلَىٰ
رَبِّكَ
فَتَخۡشَىٰ
١٩
Kí èmi sì fi ọ̀nà mọ̀ ọ́ dé ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ, kí o sì páyà (Rẹ̀).”
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:20
فاراه الاية الكبرى ٢٠
فَأَرَىٰهُ ٱلْـَٔايَةَ ٱلْكُبْرَىٰ ٢٠
فَأَرَىٰهُ
ٱلۡأٓيَةَ
ٱلۡكُبۡرَىٰ
٢٠
Ó sì fi àmì tó tóbi hàn án.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:21
فكذب وعصى ٢١
فَكَذَّبَ وَعَصَىٰ ٢١
فَكَذَّبَ
وَعَصَىٰ
٢١
(Àmọ́) ó pè é ní òpùrọ́. Ó sì yapa (rẹ̀).
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:22
ثم ادبر يسعى ٢٢
ثُمَّ أَدْبَرَ يَسْعَىٰ ٢٢
ثُمَّ
أَدۡبَرَ
يَسۡعَىٰ
٢٢
Lẹ́yìn náà, ó kẹ̀yìn sí i. Ó sì ń ṣiṣẹ́ (takò ó).
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:23
فحشر فنادى ٢٣
فَحَشَرَ فَنَادَىٰ ٢٣
فَحَشَرَ
فَنَادَىٰ
٢٣
Ó kó (àwọn ènìyàn) jọ, ó sì ké gbàjarì.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:24
فقال انا ربكم الاعلى ٢٤
فَقَالَ أَنَا۠ رَبُّكُمُ ٱلْأَعْلَىٰ ٢٤
فَقَالَ
أَنَا۠
رَبُّكُمُ
ٱلۡأَعۡلَىٰ
٢٤
Ó sì wí pé: “Èmi ni olúwa yín, ẹni gíga jùlọ.”
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:25
فاخذه الله نكال الاخرة والاولى ٢٥
فَأَخَذَهُ ٱللَّهُ نَكَالَ ٱلْـَٔاخِرَةِ وَٱلْأُولَىٰٓ ٢٥
فَأَخَذَهُ
ٱللَّهُ
نَكَالَ
ٱلۡأٓخِرَةِ
وَٱلۡأُولَىٰٓ
٢٥
Nítorí náà, Allāhu gbá a mú pẹ̀lú ìyà ìkẹ́yìn àti àkọ́kọ́ (nípa ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀ ìkẹ́yìn yìí àti àkọ́kọ́).1
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:26
ان في ذالك لعبرة لمن يخشى ٢٦
إِنَّ فِى ذَٰلِكَ لَعِبْرَةًۭ لِّمَن يَخْشَىٰٓ ٢٦
إِنَّ
فِي
ذَٰلِكَ
لَعِبۡرَةٗ
لِّمَن
يَخۡشَىٰٓ
٢٦
Dájúdájú àríwòye wà nínú ìyẹn fún ẹni tó ń páyà (Allāhu).
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:27
اانتم اشد خلقا ام السماء بناها ٢٧
ءَأَنتُمْ أَشَدُّ خَلْقًا أَمِ ٱلسَّمَآءُ ۚ بَنَىٰهَا ٢٧
ءَأَنتُمۡ
أَشَدُّ
خَلۡقًا
أَمِ
ٱلسَّمَآءُۚ
بَنَىٰهَا
٢٧
Ṣé ẹ̀yin lẹ lágbára jùlọ ní ìṣẹ̀dá ni tàbí sánmọ̀ tí Allāhu mọ?
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:28
رفع سمكها فسواها ٢٨
رَفَعَ سَمْكَهَا فَسَوَّىٰهَا ٢٨
رَفَعَ
سَمۡكَهَا
فَسَوَّىٰهَا
٢٨
Allāhu gbé àjà rẹ̀ ga sókè. Ó sì ṣe é ní pípé tó gún régé.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:29
واغطش ليلها واخرج ضحاها ٢٩
وَأَغْطَشَ لَيْلَهَا وَأَخْرَجَ ضُحَىٰهَا ٢٩
وَأَغۡطَشَ
لَيۡلَهَا
وَأَخۡرَجَ
ضُحَىٰهَا
٢٩
Ó ṣe òru rẹ̀ ní dúdú. Ó sì fa ìyálẹ̀ta rẹ̀ yọ jáde.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:30
والارض بعد ذالك دحاها ٣٠
وَٱلْأَرْضَ بَعْدَ ذَٰلِكَ دَحَىٰهَآ ٣٠
وَٱلۡأَرۡضَ
بَعۡدَ
ذَٰلِكَ
دَحَىٰهَآ
٣٠
Àti ilẹ̀, Ó tẹ́ ẹ pẹrẹsẹ lẹ́yìn ìyẹn.1
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:31
اخرج منها ماءها ومرعاها ٣١
أَخْرَجَ مِنْهَا مَآءَهَا وَمَرْعَىٰهَا ٣١
أَخۡرَجَ
مِنۡهَا
مَآءَهَا
وَمَرۡعَىٰهَا
٣١
Ó mú omi rẹ̀ àti irúgbìn rẹ̀ jáde láti inú rẹ̀.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:32
والجبال ارساها ٣٢
وَٱلْجِبَالَ أَرْسَىٰهَا ٣٢
وَٱلۡجِبَالَ
أَرۡسَىٰهَا
٣٢
Àti àwọn àpáta, Ó fi ìdí wọn múlẹ̀ ṣinṣin.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:33
متاعا لكم ولانعامكم ٣٣
مَتَـٰعًۭا لَّكُمْ وَلِأَنْعَـٰمِكُمْ ٣٣
مَتَٰعٗا
لَّكُمۡ
وَلِأَنۡعَٰمِكُمۡ
٣٣
Ìgbádùn ni fún yín àti fún àwọn ẹran-ọ̀sìn yín.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:34
فاذا جاءت الطامة الكبرى ٣٤
فَإِذَا جَآءَتِ ٱلطَّآمَّةُ ٱلْكُبْرَىٰ ٣٤
فَإِذَا
جَآءَتِ
ٱلطَّآمَّةُ
ٱلۡكُبۡرَىٰ
٣٤
Ṣùgbọ́n nígbà tí ìparun ńlá bá dé,
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:35
يوم يتذكر الانسان ما سعى ٣٥
يَوْمَ يَتَذَكَّرُ ٱلْإِنسَـٰنُ مَا سَعَىٰ ٣٥
يَوۡمَ
يَتَذَكَّرُ
ٱلۡإِنسَٰنُ
مَا
سَعَىٰ
٣٥
ní ọjọ́ tí ènìyàn yóò rántí ohun tó ṣe níṣẹ́.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:36
وبرزت الجحيم لمن يرى ٣٦
وَبُرِّزَتِ ٱلْجَحِيمُ لِمَن يَرَىٰ ٣٦
وَبُرِّزَتِ
ٱلۡجَحِيمُ
لِمَن
يَرَىٰ
٣٦
Wọ́n sì máa fi Iná hàn kedere fún (gbogbo) ẹni tó ríran.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:37
فاما من طغى ٣٧
فَأَمَّا مَن طَغَىٰ ٣٧
فَأَمَّا
مَن
طَغَىٰ
٣٧
Nítorí náà, ní ti ẹni tó tayọ ẹnu-ààlà,
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:38
واثر الحياة الدنيا ٣٨
وَءَاثَرَ ٱلْحَيَوٰةَ ٱلدُّنْيَا ٣٨
وَءَاثَرَ
ٱلۡحَيَوٰةَ
ٱلدُّنۡيَا
٣٨
tí ó tún gbé àjùlọ fún ìṣẹ̀mí ayé,
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:39
فان الجحيم هي الماوى ٣٩
فَإِنَّ ٱلْجَحِيمَ هِىَ ٱلْمَأْوَىٰ ٣٩
فَإِنَّ
ٱلۡجَحِيمَ
هِيَ
ٱلۡمَأۡوَىٰ
٣٩
dájúdájú iná Jẹhīm, òhun ni ibùgbé (rẹ̀).
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:40
واما من خاف مقام ربه ونهى النفس عن الهوى ٤٠
وَأَمَّا مَنْ خَافَ مَقَامَ رَبِّهِۦ وَنَهَى ٱلنَّفْسَ عَنِ ٱلْهَوَىٰ ٤٠
وَأَمَّا
مَنۡ
خَافَ
مَقَامَ
رَبِّهِۦ
وَنَهَى
ٱلنَّفۡسَ
عَنِ
ٱلۡهَوَىٰ
٤٠
Ní ti ẹni tí ó páyà ìdúró níwájú Olúwa rẹ̀, tí ó tún kọ ìfẹ́-inú fún ẹ̀mí (ara rẹ̀),
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:41
فان الجنة هي الماوى ٤١
فَإِنَّ ٱلْجَنَّةَ هِىَ ٱلْمَأْوَىٰ ٤١
فَإِنَّ
ٱلۡجَنَّةَ
هِيَ
ٱلۡمَأۡوَىٰ
٤١
dájúdájú Ọgbà Ìdẹ̀ra, òhun ni ibùgbé (rẹ̀).
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:42
يسالونك عن الساعة ايان مرساها ٤٢
يَسْـَٔلُونَكَ عَنِ ٱلسَّاعَةِ أَيَّانَ مُرْسَىٰهَا ٤٢
يَسۡـَٔلُونَكَ
عَنِ
ٱلسَّاعَةِ
أَيَّانَ
مُرۡسَىٰهَا
٤٢
Wọ́n ń bi ọ́ léèrè nípa Àkókò náà pé: “Ìgbà wo l’ó máa ṣẹlẹ̀?”
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:43
فيم انت من ذكراها ٤٣
فِيمَ أَنتَ مِن ذِكْرَىٰهَآ ٤٣
فِيمَ
أَنتَ
مِن
ذِكۡرَىٰهَآ
٤٣
Níbo ni ìwọ wà sí ìmọ̀ rẹ̀ ná?1
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:44
الى ربك منتهاها ٤٤
إِلَىٰ رَبِّكَ مُنتَهَىٰهَآ ٤٤
إِلَىٰ
رَبِّكَ
مُنتَهَىٰهَآ
٤٤
Ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ ni òpin ìmọ̀ nípa rẹ̀ wà.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:45
انما انت منذر من يخشاها ٤٥
إِنَّمَآ أَنتَ مُنذِرُ مَن يَخْشَىٰهَا ٤٥
إِنَّمَآ
أَنتَ
مُنذِرُ
مَن
يَخۡشَىٰهَا
٤٥
Ìwọ kúkú ni olùkìlọ̀ fún ẹni tó ń páyà rẹ̀.
Tafsirs
Lessons
Reflections
79:46
كانهم يوم يرونها لم يلبثوا الا عشية او ضحاها ٤٦
كَأَنَّهُمْ يَوْمَ يَرَوْنَهَا لَمْ يَلْبَثُوٓا۟ إِلَّا عَشِيَّةً أَوْ ضُحَىٰهَا ٤٦
كَأَنَّهُمۡ
يَوۡمَ
يَرَوۡنَهَا
لَمۡ
يَلۡبَثُوٓاْ
إِلَّا
عَشِيَّةً
أَوۡ
ضُحَىٰهَا
٤٦
Ní ọjọ́ tí wọ́n máa rí i, wọn máa dà bí ẹni pé wọn kò gbé ilé ayé tayọ ìrọ̀lẹ́ tàbí ìyálẹ̀ta (ọjọ́) kan.
Tafsirs
Lessons
Reflections

End of Chapter

Next Surah: 'AbasaTafsir of Surah An-Nazi'at
Read More
80. 'AbasaHe Frowned
Next
78. An-NabaThe Tidings
Previous
ExploreMy Quran

Achieve Your Quran Goals

Track Streaks, Create Custom Goals,
Stay Consistent

Set a Custom Goal
Next Surah: 'AbasaTafsir of Surah An-Nazi'at

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran Space
Quran.ai
Quran Audio
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute