قَالُواْ
ٱتَّخَذَ
ٱللَّهُ
وَلَدٗاۗ
سُبۡحَٰنَهُۥۖ
هُوَ
ٱلۡغَنِيُّۖ
لَهُۥ
مَا
فِي
ٱلسَّمَٰوَٰتِ
وَمَا
فِي
ٱلۡأَرۡضِۚ
إِنۡ
عِندَكُم
مِّن
سُلۡطَٰنِۭ
بِهَٰذَآۚ
أَتَقُولُونَ
عَلَى
ٱللَّهِ
مَا
لَا
تَعۡلَمُونَ
٦٨
Wọ́n wí pé: “Allāhu sọ ẹnì kan di ọmọ.” - Mímọ́ ni fún Un. Òun ní Ọlọ́rọ̀.1 TiRẹ̀ ni ohunkóhun tó wà nínú àwọn sánmọ̀ àti ohunkóhun tó wà nínú ilẹ̀. - Kò sí ẹ̀rí kan lọ́dọ̀ yín lórí èyí. Ṣé ẹ̀yin yóò máa ṣe àfitì ọ̀rọ̀ tí ẹ ò nímọ̀ rẹ̀ sọ́dọ̀ Allāhu ni?
Read Tafsir
Ibn Kathir (Abridged)
Allah is Far Above taking a Wife or having Children
Allah criticizes those who claim that He has,
وَلَداً سُبْحَنَهُ هُوَ الْغَنِيُّ
(...begotten a son. Glory is to Him! He is Rich (Free of all needs).) He is Greater than that and above it. He is Self-Sufficient, free of want or need of anything. Ever
…Allah is Far Above taking a Wife or having Children
Allah criticizes those who claim that He has,
وَلَداً سُبْحَنَهُ هُوَ الْغَنِيُّ
(...begotten a son.
…