Ash-Shu'ara 26:36 — Yoruba Translation قالوا ارجه واخاه وابعث في المداين حاشرين ٣٦
قَالُوٓاْ
أَرۡجِهۡ
وَأَخَاهُ
وَٱبۡعَثۡ
فِي
ٱلۡمَدَآئِنِ
حَٰشِرِينَ
٣٦
Wọ́n wí pé: “Dá òun àti arákùnrin rẹ̀ dúró ná, kí o sì rán àwọn akónijọ1 sí àwọn ìlú