Iniciar sesión
Iniciar sesión
Iniciar sesión
Seleccionar idioma

Al-Mursalát 77:12 لاي يوم اجلت ١٢

Página 580 · Juz 29

لِأَيِّ
يَوۡمٍ
أُجِّلَتۡ
١٢
ọjọ́ wo ni wọ́n so (àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ wọ̀nyí) rọ̀ fún ná?
reading-goal:continue-reading

Leer q-and-a.tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

Which was revealed in Makkah

The Revelation of this Surat and its Recitation in the Maghrib Prayer

Al-Bukhari recorded from `Abdullah - that is Ibn Mas`ud -- that he said, "While we were with the Messenger of Allah ﷺ in a cave at Mina,

وَالْمُرْسَلَتِ

(By the Mursalat.) was revealed to him. He was recit

…

Which was revealed in Makkah

The Revelation of this Surat and its Recitation in the Maghrib Prayer

Al-Bukhari recorded from `Abdullah - that is Ibn Mas`

…
Ver tafsirs

Leer related-content

1. Allāhu fi àwọn atẹ́gùn tó ń sáré ní tẹ̀léǹtẹ̀lé búra. 2. Ó fi àwọn ìjì atẹ́gùn tó ń jà búra. 3. Ó fi àwọn atẹ́gùn tó ń tú èṣújò ká búra. 4. Ó fi àwọn tó ń ṣèpínyà láààrin òdodo àti irọ́ búra. 5. Ó fi àwọn mọlāika tó ń mú ìrántí wá (bá àwọn Òjíṣẹ́) búra. 6. (Ìrántí náà jẹ́) àwíjàre tàbí ìkìlọ̀. 7. Dájúdájú ohun tí A ṣe ní àdéhùn fún yín kúkú máa ṣẹlẹ̀. 8. Nítorí náà, nígbà tí wọ́n bá pa (ìmọ́lẹ̀) ìràwọ̀ rẹ́, 9. àti nígbà tí wọ́n bá ṣí sánmọ̀ sílẹ̀ gbagada, 10. àti nígbà tí wọ́n bá ku àwọn àpáta dànù, 11. àti nígbà tí wọ́n bá fún àwọn Òjíṣẹ́ ní àsìkò láti kójọ (pẹ̀lú ìjọ wọn), 12. ọjọ́ wo ni wọ́n so (àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ wọ̀nyí) rọ̀ fún ná? 13. Fún ọjọ́ ìpínyà (láààrin àwọn ẹ̀dá) ni. 14. Kí sì ni ó mú ọ mọ ohun tó ń jẹ́ Ọjọ́ ìpínyà? 15. Ègbé ni ní ọjọ́ yẹn fún àwọn olùpe-òdodo-nírọ́.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

reading-goal:continue-reading

Notas y Reflexiones.

reflection-not-available

Notes placeholders

Mantente conectado al Corán ❤️

Breves recordatorios significativos para reconectar, reflexionar y mantenerse conectado con el Corán.

Lea, escuche, busque y reflexione sobre el Corán

Quran.com es una plataforma confiable utilizada por millones de personas en todo el mundo para leer, buscar, escuchar y reflexionar sobre el Corán en varios idiomas. Ofrece traducciones, tafsir, recitaciones, traducción palabra por palabra y herramientas para un estudio más profundo, haciendo que el Corán sea accesible para todos.

Como Sadaqah Jariyah, Quran.com se dedica a ayudar a las personas a conectar profundamente con el Corán. Con el apoyo de Quran.Foundation , una organización sin fines de lucro 501(c)(3), Quran.com continúa creciendo como un recurso gratuito y valioso para todos, Alhamdulillah.

Navegar
Inicio
Radio Coránica
Recitadores
Sobre nosotros
Desarrolladores
Actualizaciones de productos
Retroalimentación
Ayuda
Donar
Nuestros Proyectos
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Proyectos sin fines de lucro adquiridos, administrados o patrocinados por Quran.Foundation
Enlaces populares
Súplicas del Corán
Versículo del Corán del día
Ayatul Kursi
Yasin
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqiah
Al-Kahf
Al Muzzammil
Mapa del sitio webPrivacidadTérminos y condiciones
© 2026 Quran.com. Reservados todos los derechos
Contribuir