Sign in
Sign in
Sign in
Select Language

84. Surah Al-Inshiqaq, Yoruba Translation

The Sundering

Read the complete Surah Al-Inshiqaq with its Yoruba translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni.

Info
In the Name of Allah—the Most Compassionate, Most Merciful
84:1
اذا السماء انشقت ١
إِذَا ٱلسَّمَآءُ ٱنشَقَّتْ ١
إِذَا
ٱلسَّمَآءُ
ٱنشَقَّتۡ
١
Nígbà tí sánmọ̀ bá fàya pẹ́rẹpẹ̀rẹ
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:2
واذنت لربها وحقت ٢
وَأَذِنَتْ لِرَبِّهَا وَحُقَّتْ ٢
وَأَذِنَتۡ
لِرَبِّهَا
وَحُقَّتۡ
٢
- ó gbọ́, ó sì tẹ̀lé àṣẹ Olúwa rẹ̀ ni. Ó sì di dandan fún un láti ṣe bẹ́ẹ̀1 -
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:3
واذا الارض مدت ٣
وَإِذَا ٱلْأَرْضُ مُدَّتْ ٣
وَإِذَا
ٱلۡأَرۡضُ
مُدَّتۡ
٣
àti nígbà tí A bá fẹ ilẹ̀ lójú,
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:4
والقت ما فيها وتخلت ٤
وَأَلْقَتْ مَا فِيهَا وَتَخَلَّتْ ٤
وَأَلۡقَتۡ
مَا
فِيهَا
وَتَخَلَّتۡ
٤
ó máa ju ohun tí ó wà nínú rẹ̀ síta, ó sì máa pa sófo
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:5
واذنت لربها وحقت ٥
وَأَذِنَتْ لِرَبِّهَا وَحُقَّتْ ٥
وَأَذِنَتۡ
لِرَبِّهَا
وَحُقَّتۡ
٥
- ó gbọ́, ó sì tẹ̀lé àṣẹ Olúwa rẹ̀ ni. Ó sì di dandan fún un láti ṣe bẹ́ẹ̀ - (ní ọjọ́ yẹn ni ẹ̀dá máa rí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀)
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:6
يا ايها الانسان انك كادح الى ربك كدحا فملاقيه ٦
يَـٰٓأَيُّهَا ٱلْإِنسَـٰنُ إِنَّكَ كَادِحٌ إِلَىٰ رَبِّكَ كَدْحًۭا فَمُلَـٰقِيهِ ٦
يَٰٓأَيُّهَا
ٱلۡإِنسَٰنُ
إِنَّكَ
كَادِحٌ
إِلَىٰ
رَبِّكَ
كَدۡحٗا
فَمُلَٰقِيهِ
٦
Ìwọ ènìyàn dájúdájú ìwọ ń ṣe iṣẹ́ kárakára ní iṣẹ́ àṣepàdé Olúwa rẹ. O sì máa mú un pàdé Rẹ̀.
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:7
فاما من اوتي كتابه بيمينه ٧
فَأَمَّا مَنْ أُوتِىَ كِتَـٰبَهُۥ بِيَمِينِهِۦ ٧
فَأَمَّا
مَنۡ
أُوتِيَ
كِتَٰبَهُۥ
بِيَمِينِهِۦ
٧
Nítorí náà, ní ti ẹni tí wọ́n bá fún ní ìwé iṣẹ́ rẹ̀ ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀,
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:8
فسوف يحاسب حسابا يسيرا ٨
فَسَوْفَ يُحَاسَبُ حِسَابًۭا يَسِيرًۭا ٨
فَسَوۡفَ
يُحَاسَبُ
حِسَابٗا
يَسِيرٗا
٨
láìpẹ́ A máa ṣe ìṣírò-iṣẹ́ (rẹ̀) ní ìṣírò ìrọ̀rùn.
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:9
وينقلب الى اهله مسرورا ٩
وَيَنقَلِبُ إِلَىٰٓ أَهْلِهِۦ مَسْرُورًۭا ٩
وَيَنقَلِبُ
إِلَىٰٓ
أَهۡلِهِۦ
مَسۡرُورٗا
٩
Ó sì máa padà sí ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn rẹ̀ (nínú Ọgbà Ìdẹ̀ra) lẹ́ni ìdùnnú.
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:10
واما من اوتي كتابه وراء ظهره ١٠
وَأَمَّا مَنْ أُوتِىَ كِتَـٰبَهُۥ وَرَآءَ ظَهْرِهِۦ ١٠
وَأَمَّا
مَنۡ
أُوتِيَ
كِتَٰبَهُۥ
وَرَآءَ
ظَهۡرِهِۦ
١٠
Ní ti ẹni tí wọ́n bá sì fún ní ìwé iṣẹ́ rẹ̀ láti ẹ̀yìn rẹ̀,1
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:11
فسوف يدعو ثبورا ١١
فَسَوْفَ يَدْعُوا۟ ثُبُورًۭا ١١
فَسَوۡفَ
يَدۡعُواْ
ثُبُورٗا
١١
láìpẹ́ ó máa kígbe ìparun.
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:12
ويصلى سعيرا ١٢
وَيَصْلَىٰ سَعِيرًا ١٢
وَيَصۡلَىٰ
سَعِيرًا
١٢
Ó sì máa wọ inú Iná tó ń jó.
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:13
انه كان في اهله مسرورا ١٣
إِنَّهُۥ كَانَ فِىٓ أَهْلِهِۦ مَسْرُورًا ١٣
إِنَّهُۥ
كَانَ
فِيٓ
أَهۡلِهِۦ
مَسۡرُورًا
١٣
Dájúdájú ó ti wà láààrin àwọn ènìyàn rẹ̀ lẹ́ni ìdùnnú (sí àìgbàgbọ́ nílé ayé).
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:14
انه ظن ان لن يحور ١٤
إِنَّهُۥ ظَنَّ أَن لَّن يَحُورَ ١٤
إِنَّهُۥ
ظَنَّ
أَن
لَّن
يَحُورَ
١٤
Dájúdájú ó lérò pé òun kò níí padà (sí ọ̀dọ̀ Allāhu ni).
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:15
بلى ان ربه كان به بصيرا ١٥
بَلَىٰٓ إِنَّ رَبَّهُۥ كَانَ بِهِۦ بَصِيرًۭا ١٥
بَلَىٰٓۚ
إِنَّ
رَبَّهُۥ
كَانَ
بِهِۦ
بَصِيرٗا
١٥
Bẹ́ẹ̀ ni, (ó máa padà). Dájúdájú Olúwa rẹ̀ jẹ́ Olùríran nípa rẹ̀.
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:16
فلا اقسم بالشفق ١٦
فَلَآ أُقْسِمُ بِٱلشَّفَقِ ١٦
فَلَآ
أُقۡسِمُ
بِٱلشَّفَقِ
١٦
Nítorí náà, Èmi (Allāhu) ń fi àwòǹpapa búra.
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:17
والليل وما وسق ١٧
وَٱلَّيْلِ وَمَا وَسَقَ ١٧
وَٱلَّيۡلِ
وَمَا
وَسَقَ
١٧
Mo tún ń fi òru àti ohun tí ó kó jọ sínú rẹ̀ búra.
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:18
والقمر اذا اتسق ١٨
وَٱلْقَمَرِ إِذَا ٱتَّسَقَ ١٨
وَٱلۡقَمَرِ
إِذَا
ٱتَّسَقَ
١٨
Mo tún ń fi òṣùpá nígbà tí ó bá dégbá (tí ìmọ́lẹ̀ rẹ̀ kún) búra.
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:19
لتركبن طبقا عن طبق ١٩
لَتَرْكَبُنَّ طَبَقًا عَن طَبَقٍۢ ١٩
لَتَرۡكَبُنَّ
طَبَقًا
عَن
طَبَقٖ
١٩
Dájúdájú ẹ̀yin yóò máa bọ́ sínú wàhálà kan láti inú wàhálà kan.
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:20
فما لهم لا يومنون ٢٠
فَمَا لَهُمْ لَا يُؤْمِنُونَ ٢٠
فَمَا
لَهُمۡ
لَا
يُؤۡمِنُونَ
٢٠
Kí l’ó ṣe wọ́n ná tí wọn kò fi gbàgbọ́ ní òdodo?
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:21
واذا قري عليهم القران لا يسجدون ۩ ٢١
وَإِذَا قُرِئَ عَلَيْهِمُ ٱلْقُرْءَانُ لَا يَسْجُدُونَ ۩ ٢١
وَإِذَا
قُرِئَ
عَلَيۡهِمُ
ٱلۡقُرۡءَانُ
لَا
يَسۡجُدُونَۤ ۩
٢١
Nígbà tí wọ́n bá sì ké al-Ƙur’ān fún wọn, wọn kò níí forí kanlẹ̀.
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:22
بل الذين كفروا يكذبون ٢٢
بَلِ ٱلَّذِينَ كَفَرُوا۟ يُكَذِّبُونَ ٢٢
بَلِ
ٱلَّذِينَ
كَفَرُواْ
يُكَذِّبُونَ
٢٢
Rárá, ńṣe ni àwọn tó ṣàì gbàgbọ́ ń pè é ní irọ́.
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:23
والله اعلم بما يوعون ٢٣
وَٱللَّهُ أَعْلَمُ بِمَا يُوعُونَ ٢٣
وَٱللَّهُ
أَعۡلَمُ
بِمَا
يُوعُونَ
٢٣
Allāhu sì nímọ̀ jùlọ nípa ohun tí wọ́n ń fi pamọ́ (sínú ọkàn wọn).
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:24
فبشرهم بعذاب اليم ٢٤
فَبَشِّرْهُم بِعَذَابٍ أَلِيمٍ ٢٤
فَبَشِّرۡهُم
بِعَذَابٍ
أَلِيمٍ
٢٤
Nítorí náà, fún wọn ní ìró ìyà ẹlẹ́ta-eléro.
Tafsirs
Lessons
Reflections
84:25
الا الذين امنوا وعملوا الصالحات لهم اجر غير ممنون ٢٥
إِلَّا ٱلَّذِينَ ءَامَنُوا۟ وَعَمِلُوا۟ ٱلصَّـٰلِحَـٰتِ لَهُمْ أَجْرٌ غَيْرُ مَمْنُونٍۭ ٢٥
إِلَّا
ٱلَّذِينَ
ءَامَنُواْ
وَعَمِلُواْ
ٱلصَّٰلِحَٰتِ
لَهُمۡ
أَجۡرٌ
غَيۡرُ
مَمۡنُونِۭ
٢٥
Àyàfi àwọn tó gbàgbọ́ ní òdodo, tí wọ́n sì ṣe àwọn iṣẹ́ rere, ẹ̀san tí kò níí pin1 ń bẹ fún wọn.
Tafsirs
Lessons
Reflections

End of Chapter

Next Surah: Al-BurujTafsir of Surah Al-Inshiqaq
Read More
85. Al-BurujThe Mansions of the Stars
Next
83. Al-MutaffifinThe Defrauding
Previous
ExploreMy Quran

Achieve Your Quran Goals

Track Streaks, Create Custom Goals,
Stay Consistent

Set a Custom Goal
Next Surah: Al-BurujTafsir of Surah Al-Inshiqaq

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran Space
Quran.ai
Quran Audio
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute