Sign in
Sign in
Sign in
Select Language

69. Surah Al-Haqqah, Yoruba Translation

The Reality

Read the complete Surah Al-Haqqah with its Yoruba translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni.

Info
In the Name of Allah—the Most Compassionate, Most Merciful
69:1
الحاقة ١
ٱلْحَآقَّةُ ١
ٱلۡحَآقَّةُ
١
Ìṣẹ̀lẹ̀ Òdodo náà!
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:2
ما الحاقة ٢
مَا ٱلْحَآقَّةُ ٢
مَا
ٱلۡحَآقَّةُ
٢
Kí ni Ìṣẹ̀lẹ̀ Òdodo náà?
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:3
وما ادراك ما الحاقة ٣
وَمَآ أَدْرَىٰكَ مَا ٱلْحَآقَّةُ ٣
وَمَآ
أَدۡرَىٰكَ
مَا
ٱلۡحَآقَّةُ
٣
Kí sì ni ó mú ọ mọ ohun tó ń jẹ́ Ìṣẹ̀lẹ̀ Òdodo náà?
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:4
كذبت ثمود وعاد بالقارعة ٤
كَذَّبَتْ ثَمُودُ وَعَادٌۢ بِٱلْقَارِعَةِ ٤
كَذَّبَتۡ
ثَمُودُ
وَعَادُۢ
بِٱلۡقَارِعَةِ
٤
Àwọn ìjọ Thamūd àti ìjọ ‘Ād pe Àjíǹde (ajámọláya bí àrá) ní irọ́.1
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:5
فاما ثمود فاهلكوا بالطاغية ٥
فَأَمَّا ثَمُودُ فَأُهْلِكُوا۟ بِٱلطَّاغِيَةِ ٥
فَأَمَّا
ثَمُودُ
فَأُهۡلِكُواْ
بِٱلطَّاغِيَةِ
٥
Ní ti ìjọ Thamūd, wọ́n fi igbe tó tayọ ẹnu-ààlà pa wọ́n rẹ́.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:6
واما عاد فاهلكوا بريح صرصر عاتية ٦
وَأَمَّا عَادٌۭ فَأُهْلِكُوا۟ بِرِيحٍۢ صَرْصَرٍ عَاتِيَةٍۢ ٦
وَأَمَّا
عَادٞ
فَأُهۡلِكُواْ
بِرِيحٖ
صَرۡصَرٍ
عَاتِيَةٖ
٦
Ní ti ìjọ ‘Ād, wọ́n fi atẹ́gùn líle tó tayọ ẹnu-ààlà pa wọ́n rẹ́.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:7
سخرها عليهم سبع ليال وثمانية ايام حسوما فترى القوم فيها صرعى كانهم اعجاز نخل خاوية ٧
سَخَّرَهَا عَلَيْهِمْ سَبْعَ لَيَالٍۢ وَثَمَـٰنِيَةَ أَيَّامٍ حُسُومًۭا فَتَرَى ٱلْقَوْمَ فِيهَا صَرْعَىٰ كَأَنَّهُمْ أَعْجَازُ نَخْلٍ خَاوِيَةٍۢ ٧
سَخَّرَهَا
عَلَيۡهِمۡ
سَبۡعَ
لَيَالٖ
وَثَمَٰنِيَةَ
أَيَّامٍ
حُسُومٗاۖ
فَتَرَى
ٱلۡقَوۡمَ
فِيهَا
صَرۡعَىٰ
كَأَنَّهُمۡ
أَعۡجَازُ
نَخۡلٍ
خَاوِيَةٖ
٧
Ó dẹ ẹ́ sí wọn fún òru méje àti ọ̀sán mẹ́jọ láì dáwọ́ dúró. O sì máa rí ìjọ náà tí wọ́n ti kú sínú rẹ̀ bí ẹni pé kùkùté igi dàbínù tó ti luhò nínú ni wọ́n.1
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:8
فهل ترى لهم من باقية ٨
فَهَلْ تَرَىٰ لَهُم مِّنۢ بَاقِيَةٍۢ ٨
فَهَلۡ
تَرَىٰ
لَهُم
مِّنۢ
بَاقِيَةٖ
٨
Ǹjẹ́ o rí ẹnì kan nínú wọn tó ṣẹ́ kù bí?
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:9
وجاء فرعون ومن قبله والموتفكات بالخاطية ٩
وَجَآءَ فِرْعَوْنُ وَمَن قَبْلَهُۥ وَٱلْمُؤْتَفِكَـٰتُ بِٱلْخَاطِئَةِ ٩
وَجَآءَ
فِرۡعَوۡنُ
وَمَن
قَبۡلَهُۥ
وَٱلۡمُؤۡتَفِكَٰتُ
بِٱلۡخَاطِئَةِ
٩
Fir‘aon àti àwọn tó ṣíwájú rẹ̀ àti àwọn ìlú tí wọ́n dojú rẹ̀ bolẹ̀ dé pẹ̀lú àwọn àṣìṣe.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:10
فعصوا رسول ربهم فاخذهم اخذة رابية ١٠
فَعَصَوْا۟ رَسُولَ رَبِّهِمْ فَأَخَذَهُمْ أَخْذَةًۭ رَّابِيَةً ١٠
فَعَصَوۡاْ
رَسُولَ
رَبِّهِمۡ
فَأَخَذَهُمۡ
أَخۡذَةٗ
رَّابِيَةً
١٠
Wọ́n yapa Òjíṣẹ́ Olúwa wọn. Ó sì gbá wọn mú ní ìgbámú tóléken̄kà.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:11
انا لما طغى الماء حملناكم في الجارية ١١
إِنَّا لَمَّا طَغَا ٱلْمَآءُ حَمَلْنَـٰكُمْ فِى ٱلْجَارِيَةِ ١١
إِنَّا
لَمَّا
طَغَا
ٱلۡمَآءُ
حَمَلۡنَٰكُمۡ
فِي
ٱلۡجَارِيَةِ
١١
Dájúdájú nígbà tí omi tayọ ẹnu-ààlà. A gbe yín gun ọkọ̀ ojú-omi.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:12
لنجعلها لكم تذكرة وتعيها اذن واعية ١٢
لِنَجْعَلَهَا لَكُمْ تَذْكِرَةًۭ وَتَعِيَهَآ أُذُنٌۭ وَٰعِيَةٌۭ ١٢
لِنَجۡعَلَهَا
لَكُمۡ
تَذۡكِرَةٗ
وَتَعِيَهَآ
أُذُنٞ
وَٰعِيَةٞ
١٢
Nítorí kí Á lè fi ṣe ìrántí fún yín àti nítorí kí etí tó ń ṣọ́ n̄ǹkan lè ṣọ́ ọ.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:13
فاذا نفخ في الصور نفخة واحدة ١٣
فَإِذَا نُفِخَ فِى ٱلصُّورِ نَفْخَةٌۭ وَٰحِدَةٌۭ ١٣
فَإِذَا
نُفِخَ
فِي
ٱلصُّورِ
نَفۡخَةٞ
وَٰحِدَةٞ
١٣
Nígbà tí wọ́n bá fọn fèrè oníwo fún ikú ní fífọn ẹyọ kan,
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:14
وحملت الارض والجبال فدكتا دكة واحدة ١٤
وَحُمِلَتِ ٱلْأَرْضُ وَٱلْجِبَالُ فَدُكَّتَا دَكَّةًۭ وَٰحِدَةًۭ ١٤
وَحُمِلَتِ
ٱلۡأَرۡضُ
وَٱلۡجِبَالُ
فَدُكَّتَا
دَكَّةٗ
وَٰحِدَةٗ
١٤
tí wọ́n gbé ilẹ̀ àti àpáta sókè, tí wọ́n sì rún méjèèjì wómúwómú ní rírún ẹ̀ẹ̀ kan,
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:15
فيوميذ وقعت الواقعة ١٥
فَيَوْمَئِذٍۢ وَقَعَتِ ٱلْوَاقِعَةُ ١٥
فَيَوۡمَئِذٖ
وَقَعَتِ
ٱلۡوَاقِعَةُ
١٥
ní ọjọ́ yẹn ni Ìṣẹ̀lẹ̀ máa ṣẹlẹ̀.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:16
وانشقت السماء فهي يوميذ واهية ١٦
وَٱنشَقَّتِ ٱلسَّمَآءُ فَهِىَ يَوْمَئِذٍۢ وَاهِيَةٌۭ ١٦
وَٱنشَقَّتِ
ٱلسَّمَآءُ
فَهِيَ
يَوۡمَئِذٖ
وَاهِيَةٞ
١٦
Àti pé sánmọ̀ yó fàya pẹ́rẹpẹ̀rẹ. Ó sì máa fúyẹ́ gẹgẹ ní ọjọ́ yẹn.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:17
والملك على ارجايها ويحمل عرش ربك فوقهم يوميذ ثمانية ١٧
وَٱلْمَلَكُ عَلَىٰٓ أَرْجَآئِهَا ۚ وَيَحْمِلُ عَرْشَ رَبِّكَ فَوْقَهُمْ يَوْمَئِذٍۢ ثَمَـٰنِيَةٌۭ ١٧
وَٱلۡمَلَكُ
عَلَىٰٓ
أَرۡجَآئِهَاۚ
وَيَحۡمِلُ
عَرۡشَ
رَبِّكَ
فَوۡقَهُمۡ
يَوۡمَئِذٖ
ثَمَٰنِيَةٞ
١٧
Àwọn mọlāika sì máa wà ní àwọn ẹ̀gbẹ́ẹ̀gbẹ́ rẹ̀. Àti pé ní ọjọ́ yẹn, lókè wọn, àwọn (mọlāika) mẹ́jọ ni wọ́n máa ru Ìtẹ́ Olúwa rẹ.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:18
يوميذ تعرضون لا تخفى منكم خافية ١٨
يَوْمَئِذٍۢ تُعْرَضُونَ لَا تَخْفَىٰ مِنكُمْ خَافِيَةٌۭ ١٨
يَوۡمَئِذٖ
تُعۡرَضُونَ
لَا
تَخۡفَىٰ
مِنكُمۡ
خَافِيَةٞ
١٨
Ní ọjọ́ yẹn, wọn yóò máa ṣẹ́rí yín wá (fún ìṣírò-iṣẹ́). Kò sì níí sí àṣírí yín kan tó máa pamọ́ (fún Wa).
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:19
فاما من اوتي كتابه بيمينه فيقول هاوم اقرءوا كتابيه ١٩
فَأَمَّا مَنْ أُوتِىَ كِتَـٰبَهُۥ بِيَمِينِهِۦ فَيَقُولُ هَآؤُمُ ٱقْرَءُوا۟ كِتَـٰبِيَهْ ١٩
فَأَمَّا
مَنۡ
أُوتِيَ
كِتَٰبَهُۥ
بِيَمِينِهِۦ
فَيَقُولُ
هَآؤُمُ
ٱقۡرَءُواْ
كِتَٰبِيَهۡ
١٩
Nítorí náà, ní ti ẹni tí wọ́n bá fún ní tírà rẹ̀ ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀, ó máa sọ pé: “Ẹ gbà, ẹ ka tírà mi wò.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:20
اني ظننت اني ملاق حسابيه ٢٠
إِنِّى ظَنَنتُ أَنِّى مُلَـٰقٍ حِسَابِيَهْ ٢٠
إِنِّي
ظَنَنتُ
أَنِّي
مُلَٰقٍ
حِسَابِيَهۡ
٢٠
Dájúdájú èmi ti mọ àmọ̀dájú pé dájúdájú èmi yóò bá ìṣírò-iṣẹ́ mi pàdé.”
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:21
فهو في عيشة راضية ٢١
فَهُوَ فِى عِيشَةٍۢ رَّاضِيَةٍۢ ٢١
فَهُوَ
فِي
عِيشَةٖ
رَّاضِيَةٖ
٢١
Nítorí náà, ó máa wà nínú ìṣẹ̀mí tó máa yọ́nú sí
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:22
في جنة عالية ٢٢
فِى جَنَّةٍ عَالِيَةٍۢ ٢٢
فِي
جَنَّةٍ
عَالِيَةٖ
٢٢
nínú Ọgbà Ìdẹ̀ra gíga.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:23
قطوفها دانية ٢٣
قُطُوفُهَا دَانِيَةٌۭ ٢٣
قُطُوفُهَا
دَانِيَةٞ
٢٣
Àwọn èso rẹ̀ (sì) máa wà ní àrọ́wọ́tó.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:24
كلوا واشربوا هنييا بما اسلفتم في الايام الخالية ٢٤
كُلُوا۟ وَٱشْرَبُوا۟ هَنِيٓـًٔۢا بِمَآ أَسْلَفْتُمْ فِى ٱلْأَيَّامِ ٱلْخَالِيَةِ ٢٤
كُلُواْ
وَٱشۡرَبُواْ
هَنِيٓـَٔۢا
بِمَآ
أَسۡلَفۡتُمۡ
فِي
ٱلۡأَيَّامِ
ٱلۡخَالِيَةِ
٢٤
Ẹ jẹ, kí ẹ sì mu pẹ̀lú ìgbàdún nítorí ohun tí ẹ tì síwájú nínú àwọn ọjọ́ tí ó ti ré kọjá.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:25
واما من اوتي كتابه بشماله فيقول يا ليتني لم اوت كتابيه ٢٥
وَأَمَّا مَنْ أُوتِىَ كِتَـٰبَهُۥ بِشِمَالِهِۦ فَيَقُولُ يَـٰلَيْتَنِى لَمْ أُوتَ كِتَـٰبِيَهْ ٢٥
وَأَمَّا
مَنۡ
أُوتِيَ
كِتَٰبَهُۥ
بِشِمَالِهِۦ
فَيَقُولُ
يَٰلَيۡتَنِي
لَمۡ
أُوتَ
كِتَٰبِيَهۡ
٢٥
Ní ti ẹni tí wọ́n bá sì fún ní tírà rẹ̀ ní ọwọ́ òsì rẹ̀, ó máa wí pé: “Háà! Kí wọ́n sì má fún mi ni tírà mi!1
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:26
ولم ادر ما حسابيه ٢٦
وَلَمْ أَدْرِ مَا حِسَابِيَهْ ٢٦
وَلَمۡ
أَدۡرِ
مَا
حِسَابِيَهۡ
٢٦
Àti pé kí èmi sì má mọ ohun tí ìṣírò-iṣẹ́ mi jẹ́.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:27
يا ليتها كانت القاضية ٢٧
يَـٰلَيْتَهَا كَانَتِ ٱلْقَاضِيَةَ ٢٧
يَٰلَيۡتَهَا
كَانَتِ
ٱلۡقَاضِيَةَ
٢٧
Háà! Kí ikú sì jẹ́ òpin (ọ̀rọ̀ ẹ̀dá).
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:28
ما اغنى عني ماليه ٢٨
مَآ أَغْنَىٰ عَنِّى مَالِيَهْ ۜ ٢٨
مَآ
أَغۡنَىٰ
عَنِّي
مَالِيَهۡۜ
٢٨
Dúkìá mi kò sì rọ̀ mí lọ́rọ̀.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:29
هلك عني سلطانيه ٢٩
هَلَكَ عَنِّى سُلْطَـٰنِيَهْ ٢٩
هَلَكَ
عَنِّي
سُلۡطَٰنِيَهۡ
٢٩
Agbára mi sì ti parun.”
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:30
خذوه فغلوه ٣٠
خُذُوهُ فَغُلُّوهُ ٣٠
خُذُوهُ
فَغُلُّوهُ
٣٠
Ẹ mú un, kí ẹ dè é ní ọwọ́ mọ́ ọrùn.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:31
ثم الجحيم صلوه ٣١
ثُمَّ ٱلْجَحِيمَ صَلُّوهُ ٣١
ثُمَّ
ٱلۡجَحِيمَ
صَلُّوهُ
٣١
Lẹ́yìn náà, inú iná Jẹhīm ni kí ẹ mú un wọ̀.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:32
ثم في سلسلة ذرعها سبعون ذراعا فاسلكوه ٣٢
ثُمَّ فِى سِلْسِلَةٍۢ ذَرْعُهَا سَبْعُونَ ذِرَاعًۭا فَٱسْلُكُوهُ ٣٢
ثُمَّ
فِي
سِلۡسِلَةٖ
ذَرۡعُهَا
سَبۡعُونَ
ذِرَاعٗا
فَٱسۡلُكُوهُ
٣٢
Lẹ́yìn náà, inú ẹ̀wọ̀n tí gígùn rẹ̀ jẹ́ àádọ́rin gígùn thar‘u1 ni kí ẹ kì í sí.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:33
انه كان لا يومن بالله العظيم ٣٣
إِنَّهُۥ كَانَ لَا يُؤْمِنُ بِٱللَّهِ ٱلْعَظِيمِ ٣٣
إِنَّهُۥ
كَانَ
لَا
يُؤۡمِنُ
بِٱللَّهِ
ٱلۡعَظِيمِ
٣٣
Dájúdájú òun kì í gbàgbọ́ nínú Allāhu, Atóbi.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:34
ولا يحض على طعام المسكين ٣٤
وَلَا يَحُضُّ عَلَىٰ طَعَامِ ٱلْمِسْكِينِ ٣٤
وَلَا
يَحُضُّ
عَلَىٰ
طَعَامِ
ٱلۡمِسۡكِينِ
٣٤
Kì í sì gba ènìyàn níyànjú láti bọ́ àwọn mẹ̀kúnnù.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:35
فليس له اليوم هاهنا حميم ٣٥
فَلَيْسَ لَهُ ٱلْيَوْمَ هَـٰهُنَا حَمِيمٌۭ ٣٥
فَلَيۡسَ
لَهُ
ٱلۡيَوۡمَ
هَٰهُنَا
حَمِيمٞ
٣٥
Nítorí náà, kò níí sí ọ̀rẹ́ ìmùlẹ̀ kan fún un níbí yìí ní òní.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:36
ولا طعام الا من غسلين ٣٦
وَلَا طَعَامٌ إِلَّا مِنْ غِسْلِينٍۢ ٣٦
وَلَا
طَعَامٌ
إِلَّا
مِنۡ
غِسۡلِينٖ
٣٦
Kò sì níí sí oúnjẹ kan (fún un) bí kò ṣe (oúnjẹ) àwọnúwẹ̀jẹ̀.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:37
لا ياكله الا الخاطيون ٣٧
لَّا يَأْكُلُهُۥٓ إِلَّا ٱلْخَـٰطِـُٔونَ ٣٧
لَّا
يَأۡكُلُهُۥٓ
إِلَّا
ٱلۡخَٰطِـُٔونَ
٣٧
Kò sí ẹni tí ó máa jẹ ẹ́ bí kò ṣe àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:38
فلا اقسم بما تبصرون ٣٨
فَلَآ أُقْسِمُ بِمَا تُبْصِرُونَ ٣٨
فَلَآ
أُقۡسِمُ
بِمَا
تُبۡصِرُونَ
٣٨
Nítorí náà, Èmi ń fi ohun tí ẹ̀ ń fojú rí búra
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:39
وما لا تبصرون ٣٩
وَمَا لَا تُبْصِرُونَ ٣٩
وَمَا
لَا
تُبۡصِرُونَ
٣٩
àti ohun tí ẹ ò fojú rí.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:40
انه لقول رسول كريم ٤٠
إِنَّهُۥ لَقَوْلُ رَسُولٍۢ كَرِيمٍۢ ٤٠
إِنَّهُۥ
لَقَوۡلُ
رَسُولٖ
كَرِيمٖ
٤٠
Dájúdájú al-Ƙur’ān ni ọ̀rọ̀ (tí A fi rán) Òjíṣẹ́, alápọ̀n-ọ́nlé.1
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:41
وما هو بقول شاعر قليلا ما تومنون ٤١
وَمَا هُوَ بِقَوْلِ شَاعِرٍۢ ۚ قَلِيلًۭا مَّا تُؤْمِنُونَ ٤١
وَمَا
هُوَ
بِقَوۡلِ
شَاعِرٖۚ
قَلِيلٗا
مَّا
تُؤۡمِنُونَ
٤١
Kì í ṣe ọ̀rọ̀ eléwì. Ohun tí ẹ gbàgbọ́ kéré púpọ̀.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:42
ولا بقول كاهن قليلا ما تذكرون ٤٢
وَلَا بِقَوْلِ كَاهِنٍۢ ۚ قَلِيلًۭا مَّا تَذَكَّرُونَ ٤٢
وَلَا
بِقَوۡلِ
كَاهِنٖۚ
قَلِيلٗا
مَّا
تَذَكَّرُونَ
٤٢
Kì í sì ṣe ọ̀rọ̀ adábigba. Díẹ̀ lẹ̀ ń lò nínú ìrántí.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:43
تنزيل من رب العالمين ٤٣
تَنزِيلٌۭ مِّن رَّبِّ ٱلْعَـٰلَمِينَ ٤٣
تَنزِيلٞ
مِّن
رَّبِّ
ٱلۡعَٰلَمِينَ
٤٣
Wọ́n sọ̀ ọ́ kalẹ̀ láti ọ̀dọ̀ Olúwa gbogbo ẹ̀dá.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:44
ولو تقول علينا بعض الاقاويل ٤٤
وَلَوْ تَقَوَّلَ عَلَيْنَا بَعْضَ ٱلْأَقَاوِيلِ ٤٤
وَلَوۡ
تَقَوَّلَ
عَلَيۡنَا
بَعۡضَ
ٱلۡأَقَاوِيلِ
٤٤
Tí ó bá jẹ́ pé (Ànábì - kí ìkẹ́ àti ọlà Allāhu máa bá a - ) dá àdápa apá kan ọ̀rọ̀ náà mọ́ Wa ni,
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:45
لاخذنا منه باليمين ٤٥
لَأَخَذْنَا مِنْهُ بِٱلْيَمِينِ ٤٥
لَأَخَذۡنَا
مِنۡهُ
بِٱلۡيَمِينِ
٤٥
Àwa ìbá gbá a mú lọ́wọ́ ọ̀tún.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:46
ثم لقطعنا منه الوتين ٤٦
ثُمَّ لَقَطَعْنَا مِنْهُ ٱلْوَتِينَ ٤٦
ثُمَّ
لَقَطَعۡنَا
مِنۡهُ
ٱلۡوَتِينَ
٤٦
Lẹ́yìn náà, Àwa ìbá já isan ọrùn rẹ̀.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:47
فما منكم من احد عنه حاجزين ٤٧
فَمَا مِنكُم مِّنْ أَحَدٍ عَنْهُ حَـٰجِزِينَ ٤٧
فَمَا
مِنكُم
مِّنۡ
أَحَدٍ
عَنۡهُ
حَٰجِزِينَ
٤٧
Kò sì sí ẹnì kan nínú yín tí ó máa gbà á sílẹ̀ lọ́wọ́ (Wa).
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:48
وانه لتذكرة للمتقين ٤٨
وَإِنَّهُۥ لَتَذْكِرَةٌۭ لِّلْمُتَّقِينَ ٤٨
وَإِنَّهُۥ
لَتَذۡكِرَةٞ
لِّلۡمُتَّقِينَ
٤٨
Dájúdájú (al-Ƙur’ān) ni ìrántí fún àwọn olùbẹ̀rù (Allāhu).
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:49
وانا لنعلم ان منكم مكذبين ٤٩
وَإِنَّا لَنَعْلَمُ أَنَّ مِنكُم مُّكَذِّبِينَ ٤٩
وَإِنَّا
لَنَعۡلَمُ
أَنَّ
مِنكُم
مُّكَذِّبِينَ
٤٩
Dájúdájú Àwa sì mọ̀ pé àwọn tó ń pe al-Ƙur’ān ní irọ́ wà nínú yín.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:50
وانه لحسرة على الكافرين ٥٠
وَإِنَّهُۥ لَحَسْرَةٌ عَلَى ٱلْكَـٰفِرِينَ ٥٠
وَإِنَّهُۥ
لَحَسۡرَةٌ
عَلَى
ٱلۡكَٰفِرِينَ
٥٠
Dájúdájú al-Ƙur’ān máa jẹ́ àbámọ̀ ńlá fún àwọn aláìgbàgbọ́.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:51
وانه لحق اليقين ٥١
وَإِنَّهُۥ لَحَقُّ ٱلْيَقِينِ ٥١
وَإِنَّهُۥ
لَحَقُّ
ٱلۡيَقِينِ
٥١
Dájúdájú al-Ƙur’ān ni òdodo tó dájú.
Tafsirs
Lessons
Reflections
69:52
فسبح باسم ربك العظيم ٥٢
فَسَبِّحْ بِٱسْمِ رَبِّكَ ٱلْعَظِيمِ ٥٢
فَسَبِّحۡ
بِٱسۡمِ
رَبِّكَ
ٱلۡعَظِيمِ
٥٢
Nítorí náà, ṣàfọ̀mọ́ fún orúkọ Olúwa Rẹ, Atóbi.
Tafsirs
Lessons
Reflections

End of Chapter

Next Surah: Al-Ma'arijTafsir of Surah Al-Haqqah
Read More
70. Al-Ma'arijThe Ascending Stairways
Next
68. Al-QalamThe Pen
Previous
ExploreMy Quran

Achieve Your Quran Goals

Track Streaks, Create Custom Goals,
Stay Consistent

Set a Custom Goal
Next Surah: Al-Ma'arijTafsir of Surah Al-Haqqah

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran Space
Quran.ai
Quran Audio
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute