Adh-Dhariyat 51:28 — Yoruba Translation فاوجس منهم خيفة قالوا لا تخف وبشروه بغلام عليم ٢٨
فَأَوۡجَسَ
مِنۡهُمۡ
خِيفَةٗۖ
قَالُواْ
لَا
تَخَفۡۖ
وَبَشَّرُوهُ
بِغُلَٰمٍ
عَلِيمٖ
٢٨
Nígbà náà, ìbẹ̀rù wọn sì mú un.1. Wọ́n sọ pé: “Má ṣe páyà.” Wọ́n sì fún un ní ìró ìdùnnú nípa bíbí ọmọkùnrin kan tí ó máa ní ìmọ̀.