Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
English
العربية
বাংলা
فارسی
Français
Indonesia
Italiano
Dutch
Português
русский
Shqip
ภาษาไทย
Türkçe
اردو
简体中文
Melayu
Español
Kiswahili
Tiếng Việt
80. chapter:full-surah-seo-heading
He Frowned
chapter:full-surah-seo-visible-intro quran-reader:translation-by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni.
Listen
info
Translation
bismillah
80:1
عبس وتولى ١
عَبَسَ وَتَوَلَّىٰٓ ١
عَبَسَ
وَتَوَلَّىٰٓ
١
Ó fajú ro, ó sì pẹ̀yìndà
1
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:2
ان جاءه الاعمى ٢
أَن جَآءَهُ ٱلْأَعْمَىٰ ٢
أَن
جَآءَهُ
ٱلۡأَعۡمَىٰ
٢
nítorí pé afọ́jú wá bá a.
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:3
وما يدريك لعله يزكى ٣
وَمَا يُدْرِيكَ لَعَلَّهُۥ يَزَّكَّىٰٓ ٣
وَمَا
يُدۡرِيكَ
لَعَلَّهُۥ
يَزَّكَّىٰٓ
٣
Kí sì l’ó máa fi mọ̀ ọ́ pé ó ṣeé ṣe kí ó ṣàfọ̀mọ́ (ara rẹ̀ kúrò nínú àìgbàgbọ́)
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:4
او يذكر فتنفعه الذكرى ٤
أَوْ يَذَّكَّرُ فَتَنفَعَهُ ٱلذِّكْرَىٰٓ ٤
أَوۡ
يَذَّكَّرُ
فَتَنفَعَهُ
ٱلذِّكۡرَىٰٓ
٤
tàbí kí ó gbọ́ ìrántí, kí ìrántí náà sì ṣe é ní àǹfààní?
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:5
اما من استغنى ٥
أَمَّا مَنِ ٱسْتَغْنَىٰ ٥
أَمَّا
مَنِ
ٱسۡتَغۡنَىٰ
٥
Ní ti ẹni tí ó ka ara rẹ̀ kún ọlọ́rọ̀,
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:6
فانت له تصدى ٦
فَأَنتَ لَهُۥ تَصَدَّىٰ ٦
فَأَنتَ
لَهُۥ
تَصَدَّىٰ
٦
òun ni ìwọ tẹ́tí sí.
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:7
وما عليك الا يزكى ٧
وَمَا عَلَيْكَ أَلَّا يَزَّكَّىٰ ٧
وَمَا
عَلَيۡكَ
أَلَّا
يَزَّكَّىٰ
٧
Kò sì sí ẹ̀ṣẹ̀ fún ọ bí kò bá ṣe àfọ̀mọ́ (ara rẹ̀ kúrò nínú àìgbàgbọ́).
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:8
واما من جاءك يسعى ٨
وَأَمَّا مَن جَآءَكَ يَسْعَىٰ ٨
وَأَمَّا
مَن
جَآءَكَ
يَسۡعَىٰ
٨
Ní ti ẹni tí ó sì wá bá ọ, tó ń yára gágá (sí ìrántí, ìyẹn afọ́jú),
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:9
وهو يخشى ٩
وَهُوَ يَخْشَىٰ ٩
وَهُوَ
يَخۡشَىٰ
٩
tí ó sì ń páyà (Allāhu),
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:10
فانت عنه تلهى ١٠
فَأَنتَ عَنْهُ تَلَهَّىٰ ١٠
فَأَنتَ
عَنۡهُ
تَلَهَّىٰ
١٠
ìwọ kò sì kọbi ara sí i.
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:11
كلا انها تذكرة ١١
كَلَّآ إِنَّهَا تَذْكِرَةٌۭ ١١
كـَلَّآ
إِنَّهَا
تَذۡكِرَةٞ
١١
Rárá (kò tọ́ bẹ́ẹ̀). Dájúdájú al-Ƙur’ān ni ìrántí.
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:12
فمن شاء ذكره ١٢
فَمَن شَآءَ ذَكَرَهُۥ ١٢
فَمَن
شَآءَ
ذَكَرَهُۥ
١٢
Nítorí náà, ẹni tí ó bá fẹ́ kí ó rántí rẹ̀.
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:13
في صحف مكرمة ١٣
فِى صُحُفٍۢ مُّكَرَّمَةٍۢ ١٣
فِي
صُحُفٖ
مُّكَرَّمَةٖ
١٣
(Al-Ƙur’ān) wà nínú àwọn tàkádà alápọ̀n-ọ́nlé,
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:14
مرفوعة مطهرة ١٤
مَّرْفُوعَةٍۢ مُّطَهَّرَةٍۭ ١٤
مَّرۡفُوعَةٖ
مُّطَهَّرَةِۭ
١٤
A gbé e ga, A sì ṣe é ní mímọ́
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:15
بايدي سفرة ١٥
بِأَيْدِى سَفَرَةٍۢ ١٥
بِأَيۡدِي
سَفَرَةٖ
١٥
ní ọwọ́ àwọn òǹkọtíà (ìyẹn, àwọn mọlāika),
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:16
كرام بررة ١٦
كِرَامٍۭ بَرَرَةٍۢ ١٦
كِرَامِۭ
بَرَرَةٖ
١٦
àwọn alápọ̀n-ọ́nlé, àwọn ẹni rere.
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:17
قتل الانسان ما اكفره ١٧
قُتِلَ ٱلْإِنسَـٰنُ مَآ أَكْفَرَهُۥ ١٧
قُتِلَ
ٱلۡإِنسَٰنُ
مَآ
أَكۡفَرَهُۥ
١٧
Wọ́n ti fi ènìyàn gégùn-ún (nípa) bí ó ṣe jẹ́ aláìmoore jùlọ!
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:18
من اي شيء خلقه ١٨
مِنْ أَىِّ شَىْءٍ خَلَقَهُۥ ١٨
مِنۡ
أَيِّ
شَيۡءٍ
خَلَقَهُۥ
١٨
Kí sì ni Allāhu fi ṣẹ̀dá rẹ̀?
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:19
من نطفة خلقه فقدره ١٩
مِن نُّطْفَةٍ خَلَقَهُۥ فَقَدَّرَهُۥ ١٩
مِن
نُّطۡفَةٍ
خَلَقَهُۥ
فَقَدَّرَهُۥ
١٩
Nínú àtọ̀ l’Ó ti ṣẹ̀dá rẹ̀. Ó sì pèbùbù (ẹ̀yà-ara) rẹ̀.
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:20
ثم السبيل يسره ٢٠
ثُمَّ ٱلسَّبِيلَ يَسَّرَهُۥ ٢٠
ثُمَّ
ٱلسَّبِيلَ
يَسَّرَهُۥ
٢٠
Lẹ́yìn náà, Ó ṣe ọ̀nà àtiwáyé ní ìrọ̀rùn fún un.
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:21
ثم اماته فاقبره ٢١
ثُمَّ أَمَاتَهُۥ فَأَقْبَرَهُۥ ٢١
ثُمَّ
أَمَاتَهُۥ
فَأَقۡبَرَهُۥ
٢١
Lẹ́yìn náà, Ó máa pa á. Ó sì máa fi sínú sàréè.
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:22
ثم اذا شاء انشره ٢٢
ثُمَّ إِذَا شَآءَ أَنشَرَهُۥ ٢٢
ثُمَّ
إِذَا
شَآءَ
أَنشَرَهُۥ
٢٢
Lẹ́yìn náà, nígbà tí Allāhu bá fẹ́, Ó máa gbé e dìde.
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:23
كلا لما يقض ما امره ٢٣
كَلَّا لَمَّا يَقْضِ مَآ أَمَرَهُۥ ٢٣
كـَلَّا
لَمَّا
يَقۡضِ
مَآ
أَمَرَهُۥ
٢٣
Rárá o! Ènìyàn kò tí ì ṣe n̄ǹkan tí Allāhu pa láṣẹ fún un.
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:24
فلينظر الانسان الى طعامه ٢٤
فَلْيَنظُرِ ٱلْإِنسَـٰنُ إِلَىٰ طَعَامِهِۦٓ ٢٤
فَلۡيَنظُرِ
ٱلۡإِنسَٰنُ
إِلَىٰ
طَعَامِهِۦٓ
٢٤
Nítorí náà, kí ènìyàn wòye sí oúnjẹ rẹ̀.
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:25
انا صببنا الماء صبا ٢٥
اَنَّا صَبَبْنَا ٱلْمَآءَ صَبًّۭا ٢٥
أَنَّا
صَبَبۡنَا
ٱلۡمَآءَ
صَبّٗا
٢٥
Dájúdájú Àwa ń rọ òjò ní púpọ̀.
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:26
ثم شققنا الارض شقا ٢٦
ثُمَّ شَقَقْنَا ٱلْأَرْضَ شَقًّۭا ٢٦
ثُمَّ
شَقَقۡنَا
ٱلۡأَرۡضَ
شَقّٗا
٢٦
Lẹ́yìn náà, A mú ilẹ̀ sán kànkàn.
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:27
فانبتنا فيها حبا ٢٧
فَأَنۢبَتْنَا فِيهَا حَبًّۭا ٢٧
فَأَنۢبَتۡنَا
فِيهَا
حَبّٗا
٢٧
A sì mú kóró èso hù jáde láti inú rẹ̀;
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:28
وعنبا وقضبا ٢٨
وَعِنَبًۭا وَقَضْبًۭا ٢٨
وَعِنَبٗا
وَقَضۡبٗا
٢٨
àti èso àjàrà àti kànnáfùrù,
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:29
وزيتونا ونخلا ٢٩
وَزَيْتُونًۭا وَنَخْلًۭا ٢٩
وَزَيۡتُونٗا
وَنَخۡلٗا
٢٩
àti igi òróró Zaetūn àti dàbínù,
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:30
وحدايق غلبا ٣٠
وَحَدَآئِقَ غُلْبًۭا ٣٠
وَحَدَآئِقَ
غُلۡبٗا
٣٠
àti àwọn ọgbà tó kún fún igi,
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:31
وفاكهة وابا ٣١
وَفَـٰكِهَةًۭ وَأَبًّۭا ٣١
وَفَٰكِهَةٗ
وَأَبّٗا
٣١
àti àwọn èso (mìíràn) pẹ̀lú ewé tí ẹranko ń jẹ, (A mú wọn hù jáde).
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:32
متاعا لكم ولانعامكم ٣٢
مَّتَـٰعًۭا لَّكُمْ وَلِأَنْعَـٰمِكُمْ ٣٢
مَّتَٰعٗا
لَّكُمۡ
وَلِأَنۡعَٰمِكُمۡ
٣٢
(Wọ́n jẹ́ n̄ǹkan) ìgbádùn fún ẹ̀yin àti àwọn ẹran-ọ̀sìn yín.
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:33
فاذا جاءت الصاخة ٣٣
فَإِذَا جَآءَتِ ٱلصَّآخَّةُ ٣٣
فَإِذَا
جَآءَتِ
ٱلصَّآخَّةُ
٣٣
Nígbà tí fífọn sínú ìwo nígbà kejì bá ṣẹlẹ̀,
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:34
يوم يفر المرء من اخيه ٣٤
يَوْمَ يَفِرُّ ٱلْمَرْءُ مِنْ أَخِيهِ ٣٤
يَوۡمَ
يَفِرُّ
ٱلۡمَرۡءُ
مِنۡ
أَخِيهِ
٣٤
ní ọjọ́ tí ènìyàn yóò sá fún arákùnrin rẹ̀,
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:35
وامه وابيه ٣٥
وَأُمِّهِۦ وَأَبِيهِ ٣٥
وَأُمِّهِۦ
وَأَبِيهِ
٣٥
àti ìyá rẹ̀ àti bàbá rẹ̀,
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:36
وصاحبته وبنيه ٣٦
وَصَـٰحِبَتِهِۦ وَبَنِيهِ ٣٦
وَصَٰحِبَتِهِۦ
وَبَنِيهِ
٣٦
àti ìyàwó rẹ̀ àti àwọn ọmọ rẹ̀.
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:37
لكل امري منهم يوميذ شان يغنيه ٣٧
لِكُلِّ ٱمْرِئٍۢ مِّنْهُمْ يَوْمَئِذٍۢ شَأْنٌۭ يُغْنِيهِ ٣٧
لِكُلِّ
ٱمۡرِيٕٖ
مِّنۡهُمۡ
يَوۡمَئِذٖ
شَأۡنٞ
يُغۡنِيهِ
٣٧
Ẹnì kọ̀ọ̀kan wọn ní ọjọ́ yẹn l’ó ti ní ọ̀ràn tó máa tó o ó rán.
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:38
وجوه يوميذ مسفرة ٣٨
وُجُوهٌۭ يَوْمَئِذٍۢ مُّسْفِرَةٌۭ ٣٨
وُجُوهٞ
يَوۡمَئِذٖ
مُّسۡفِرَةٞ
٣٨
Àwọn ojú kan lọ́jọ́ yẹn yóò mọ́lẹ̀.
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:39
ضاحكة مستبشرة ٣٩
ضَاحِكَةٌۭ مُّسْتَبْشِرَةٌۭ ٣٩
ضَاحِكَةٞ
مُّسۡتَبۡشِرَةٞ
٣٩
Wọn yó máa rẹ́rìn-ín, wọn yó sì máa dunnú.
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:40
ووجوه يوميذ عليها غبرة ٤٠
وَوُجُوهٌۭ يَوْمَئِذٍ عَلَيْهَا غَبَرَةٌۭ ٤٠
وَوُجُوهٞ
يَوۡمَئِذٍ
عَلَيۡهَا
غَبَرَةٞ
٤٠
Àwọn ojú kan lọ́jọ́ yẹn ni eruku yó sì bò mọ́lẹ̀.
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections
80:1
عبس وتولى ١
عَبَسَ وَتَوَلَّىٰٓ ١
عَبَسَ
وَتَوَلَّىٰٓ
١
Ó fajú ro, ó sì pẹ̀yìndà
1
quran-reader:tafsirs
Lessons
Reflections