Ingia
Ingia
Ingia
Chagua Lugha

Al-Waqiah 56:43 وظل من يحموم ٤٣

Ukurasa 535 · Juzuu 27

وَظِلّٖ
مِّن
يَحۡمُومٖ
٤٣
àti ní abẹ́ ibòji eléèéfín dúdú,
reading-goal:continue-reading

Soma q-and-a.tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

Those on the Left and Their Recompense

After Allah mentioned the condition of those on the right hand, He then mentioned the condition of those on the left hand,

وَأَصْحَبُ الشِّمَالِ مَآ أَصْحَبُ الشِّمَالِ

(And those on the left How will be those on the left) meaning, `What is the condition of those

…

Those on the Left and Their Recompense

After Allah mentioned the condition of those on the right hand, He then mentioned the condition of those on the

…
Tazama tafsirs

Soma related-content

41. Àwọn èrò ọwọ́ òsì, kí ni (ó máa ti burú tó fún) àwọn èrò ọwọ́ òsì? 42. (Wọn yóò wà) nínú atẹ́gùn gbígbóná (iná) àti omi tó gbóná parí, 43. àti ní abẹ́ ibòji eléèéfín dúdú, 44. kò tutù, kò sì dára. 45. Dájúdájú wọ́n ti jẹ́ onígbẹdẹmukẹ ṣíwájú ìyẹn. 46. Wọ́n sì máa ń ṣoríkunkun lórí ẹ̀ṣẹ̀ ńlá. 47. Wọ́n sì máa ń wí pé: “Ṣé nígbà tí a bá di òkú, tí a sì di erùpẹ̀ àti egungun, ǹjẹ́ Wọn yóò tún gbé wa dìde ni? 48. Ṣé àti àwọn bàbá wa, àwọn ẹni àkọ́kọ́?” 49. Sọ pé: “Dájúdájú àwọn ẹni àkọ́kọ́ àti àwọn ẹni Ìkẹ́yìn, 50. dájúdájú A óò kó wọn jọ papọ̀ ní àkókò ọjọ́ kan tí A ti mọ̀.” 51. Lẹ́yìn náà, dájúdájú ẹ̀yin olùṣìnà, olùpe-òdodo-nírọ́, 52. dájúdájú ẹ̀yin máa jẹ nínú igi zaƙƙūm (igi iwọ). 53. Ikùn yín sì máa kún bámúbámú fún (jíjẹ) igi náà. 54. Ẹ̀yin yó sì máa mu omi tó gbóná parí lé e lórí. 55. Ẹ̀yin yóò máa mu ún ní ìmumi ràkúnmí tí òǹgbẹ ń gbẹ. 56. Èyí ni n̄ǹkan àlejò wọn ní Ọjọ́ ẹ̀san.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

reading-goal:continue-reading

Maelezo na Tafakari

reflection-not-available

Notes placeholders

Endelea Kuungana na Qur'ani ❤️

Vikumbusho vifupi vyenye maana vinavyoweka upya maisha yako, kukusaidia kutafakari na kuendelea kushikamana na Qur'ani.

Soma, Sikiliza, Tafuta, na Tafakari Qur'ani

Quran.com ni jukwaa linaloaminika na linalotumiwa na mamilioni duniani kote kusoma, kutafuta, kusikiliza na kutafakari kuhusu Qur'ani katika lugha tofauti. Inatoa huduma za tarjuma, tafsiri, vikariri, tarjuma ya neno kwa neno, na zana za ufahamu wa kina, kuifanya Qur'ani ipatikane na kila mtu.

Kama mbinu ya Sadaqah Jariyah, Quran.com imejitolea kusaidia watu kuunganishwa kwa kina na Qur'ani. Ikiungwa mkono na Quran.Foundation , shirika lisilo la faida la 501(c)(3), Quran.com inaendelea kukua kama rasilimali ya bila malipo na yenye thamani kwa wote, Alhamdulillah.

Chunguza
Nyumbani
Redio ya Qur'ani
Wasomaji
Kutuhusu
Watengenezaji
Sasisho za Bidhaa
Maoni
Msaada
Changia
Miradi Yetu
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Miradi isiyo ya faida inayomilikiwa, kusimamiwa, au kufadhiliwa na Quran.Foundation
Viungo Maarufu
Dua kutoka Quran
Aya ya Quran ya Siku
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
Ramani ya tovutiFaraghaSheria na Masharti
© 2026 Quran.com. Haki Zote Zimehifadhiwa
Changia