Iniciar sesión
Iniciar sesión
Iniciar sesión
Seleccionar idioma

Al-Qiyáma 75:37 الم يك نطفة من مني يمنى ٣٧

Página 578 · Juz 29

أَلَمۡ
يَكُ
نُطۡفَةٗ
مِّن
مَّنِيّٖ
يُمۡنَىٰ
٣٧
Ṣé kò ti jẹ́ àtọ̀ mọnī tí wọ́n dà jáde sínú àpòlùkẹ́ ni?
reading-goal:continue-reading

Leer q-and-a.tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

Certainty will Occur at the Time of Death. Allah Informs of the Condition at the Time of Death and What Terrors it Contains.

May Allah make us firm at that time with the Firm Statement. Allah says,

كَلاَّ إِذَا بَلَغَتِ التَّرَاقِىَ

(Nay, when it reaches to the collarbones.) If we make the word "Kalla"

…

Certainty will Occur at the Time of Death. Allah Informs of the Condition at the Time of Death and What Terrors it Contains.

May Allah make us firm at

…
Ver tafsirs

Leer related-content

26. Kò rí bẹ́ẹ̀, nígbà tí ẹ̀mí bá dé gògòńgò. 27. A sì máa sọ pé: “Ǹjẹ́ olùpọfọ̀ kan wà bí (tí ó máa pọfọ̀ láti gbà á sílẹ̀ lọ́wọ́ ikú)? 28. Ó sì máa dá a lójú pé dájúdájú ìpínyà ayé ti dé. 29. Ojúgun yó sì lọ́mọ́ ojúgun. 30. Ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ sì ni wíwa ẹ̀dá lọ ní ọjọ́ yẹn. 31. Kò kúkú gba òdodo gbọ́, kò sì kírun. 32. Ṣùgbọ́n ó pe òdodo ní irọ́. Ó sì kẹ̀yìn sí i. 33. Lẹ́yìn náà, ó lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn rẹ̀, ó sì ń ṣe fáàrí. 34. (Ìparun nílé ayé) ló tọ́ sí ọ jùlọ (lórí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ wọ̀nyẹn). (Ìyẹn) ló sì tọ́ sí ọ jùlọ. 35. Lẹ́yìn náà, (Iná) ló tọ́ sí ọ jùlọ (ní ọ̀run). (Ìyẹn) ló sì tọ́ sí ọ jùlọ. 36. Ṣé ènìyàn lérò pé A máa fi òun sílẹ̀ lásán ni? 37. Ṣé kò ti jẹ́ àtọ̀ mọnī tí wọ́n dà jáde sínú àpòlùkẹ́ ni? 38. Lẹ́yìn náà, ó di ẹ̀jẹ̀ dídì. (Allāhu) sì ṣẹ̀dá (rẹ̀). Ó sì ṣe é tó dọ́gba jálẹ̀ léèyàn. 39. (Allāhu) sì ṣe ìran méjì jáde láti ara rẹ̀, akọ àti abo. 40. Ǹjẹ́ Ẹni tí Ó ṣe ìyẹn kò níí ní agbára láti jí àwọn òkú dìde bí?

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

reading-goal:continue-reading

Notas y Reflexiones.

reflection-not-available

Notes placeholders

Mantente conectado al Corán ❤️

Breves recordatorios significativos para reconectar, reflexionar y mantenerse conectado con el Corán.

Lea, escuche, busque y reflexione sobre el Corán

Quran.com es una plataforma confiable utilizada por millones de personas en todo el mundo para leer, buscar, escuchar y reflexionar sobre el Corán en varios idiomas. Ofrece traducciones, tafsir, recitaciones, traducción palabra por palabra y herramientas para un estudio más profundo, haciendo que el Corán sea accesible para todos.

Como Sadaqah Jariyah, Quran.com se dedica a ayudar a las personas a conectar profundamente con el Corán. Con el apoyo de Quran.Foundation , una organización sin fines de lucro 501(c)(3), Quran.com continúa creciendo como un recurso gratuito y valioso para todos, Alhamdulillah.

Navegar
Inicio
Radio Coránica
Recitadores
Sobre nosotros
Desarrolladores
Actualizaciones de productos
Retroalimentación
Ayuda
Donar
Nuestros Proyectos
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Proyectos sin fines de lucro adquiridos, administrados o patrocinados por Quran.Foundation
Enlaces populares
Súplicas del Corán
Versículo del Corán del día
Ayatul Kursi
Yasin
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqiah
Al-Kahf
Al Muzzammil
Mapa del sitio webPrivacidadTérminos y condiciones
© 2026 Quran.com. Reservados todos los derechos
Contribuir