Ingia
Ingia
Ingia
Chagua Lugha

Al-Qalam 68:11 هماز مشاء بنميم ١١

Ukurasa 564 · Juzuu 29

هَمَّازٖ
مَّشَّآءِۭ
بِنَمِيمٖ
١١
abúni, alárìnká tó ń sòfófó kiri,
Endelea Kusoma

Soma Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

Prohibition of giving in to the Pressure of the Disbelievers and Their Suggestions, and that They like to meet in the Middle of the Path

Allah says, `just as We have favored you and given you the upright legislation and great (standard of) character,'

فَلاَ تُطِعِ الْمُكَذِّبِينَ - وَدُّواْ لَوْ تُدْه

…

Prohibition of giving in to the Pressure of the Disbelievers and Their Suggestions, and that They like to meet in the Middle of the Path

Allah says, `j

…
Tazama Tafsir

Soma katika Muktadha

1. Nūn. (Allāhu ló mọ ohun tí Ó gbàlérò pẹ̀lú háràfí náà.) Allāhu fi gègé ìkọ̀wé àti ohun tí àwọn mọlāika ń kọ sílẹ̀ búra. 2. Ìwọ kì í ṣe wèrè nípa ìdẹ̀ra Olúwa rẹ. 3. Àti pé dájúdájú ẹ̀san tí kò níí dáwọ́ dúró ti wà fún ọ. 4. Dájúdájú ìwọ sì wà lórí ìwà ńlá (ìwà alápọ̀n-ọ́nlé). 5. Láìpẹ́ ìwọ yóò rí i, àwọn náà yó sì rí i; 6. èwo nínú yín ni aládàn-ánwò (wèrè)? 7. Dájúdájú Olúwa rẹ, Ó nímọ̀ jùlọ nípa ẹni tó ṣìnà kúrò lójú ọ̀nà Rẹ̀. Ó sì nímọ̀ jùlọ nípa àwọn olùmọ̀nà. 8. Nítorí náà, má ṣe tẹ̀lé àwọn olùpe-òdodo-nírọ́. 9. Àti pé wọ́n fẹ́ kí o dẹwọ́, kí àwọn náà sì dẹwọ́. 10. Má ṣe tẹ̀lé gbogbo ẹni tí ìbúra rẹ̀ pọ̀, ẹni yẹpẹrẹ, 11. abúni, alárìnká tó ń sòfófó kiri, 12. olùdènà iṣẹ́ rere, alákọyọ, ẹlẹ́ṣẹ̀, 13. ọ̀dájú. Lẹ́yìn ìyẹn, ògbólógbòó ẹni ibi (àsáwọ̀, ọmọ zina) ni. 14. Nítorí pé ó ní dúkìá àti àwọn ọmọkùnrin, 15. nígbà tí wọ́n bá ń ké àwọn āyah Wa fún un, ó máa wí pé: “Àkọsílẹ̀ àlọ́ àwọn ẹni àkọ́kọ́ (nìwọ̀nyí)”. 16. A máa fi àmì sí i ní góńgórí imú.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Endelea Kusoma

Maelezo na Tafakari

Huna maelezo au tafakari yoyote kuhusu aya hii.

Notes placeholders

Endelea Kuungana na Qur'ani ❤️

Vikumbusho vifupi vyenye maana vinavyoweka upya maisha yako, kukusaidia kutafakari na kuendelea kushikamana na Qur'ani.

Soma, Sikiliza, Tafuta, na Tafakari Qur'ani

Quran.com ni jukwaa linaloaminika na linalotumiwa na mamilioni duniani kote kusoma, kutafuta, kusikiliza na kutafakari kuhusu Qur'ani katika lugha tofauti. Inatoa huduma za tarjuma, tafsiri, vikariri, tarjuma ya neno kwa neno, na zana za ufahamu wa kina, kuifanya Qur'ani ipatikane na kila mtu.

Kama mbinu ya Sadaqah Jariyah, Quran.com imejitolea kusaidia watu kuunganishwa kwa kina na Qur'ani. Ikiungwa mkono na Quran.Foundation , shirika lisilo la faida la 501(c)(3), Quran.com inaendelea kukua kama rasilimali ya bila malipo na yenye thamani kwa wote, Alhamdulillah.

Chunguza
Nyumbani
Redio ya Qur'ani
Wasomaji
Kutuhusu
Watengenezaji
Sasisho za Bidhaa
Maoni
Msaada
Changia
Miradi Yetu
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Miradi isiyo ya faida inayomilikiwa, kusimamiwa, au kufadhiliwa na Quran.Foundation
Viungo Maarufu
Dua kutoka Quran
Aya ya Quran ya Siku
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
Ramani ya tovutiFaraghaSheria na Masharti
© 2026 Quran.com. Haki Zote Zimehifadhiwa
Changia