Log masuk
Log masuk
Log masuk
Pilih Bahasa

Al-Ma'aarij 70:28 ان عذاب ربهم غير مامون ٢٨

Halaman 569 · Juz 29

إِنَّ
عَذَابَ
رَبِّهِمۡ
غَيۡرُ
مَأۡمُونٖ
٢٨
dájúdájú ìyà Olúwa wọn kò ṣeé fàyàbalẹ̀ sí;
reading-goal:continue-reading

Baca q-and-a.tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

Man is Impatient Allah informs about man and his inclination to corrupt his behavior.

Allah says,

إِنَّ الإِنسَنَ خُلِقَ هَلُوعاً

(Verily, man was created very impatient;) Then, Allah explains this statement by saying,

إِذَا مَسَّهُ الشَّرُّ جَزُوعاً

(Apprehensive when evil touches him;) meaning, wheneve

…

Man is Impatient Allah informs about man and his inclination to corrupt his behavior.

Allah says,

إِنَّ الإِنسَنَ خُلِقَ هَلُوعاً

(Verily, man was create

…
Lihat tafsirs

Baca related-content

19. Dájúdájú ènìyàn, A ṣẹ̀dá rẹ̀ ní aláìlọ́kàn, ọ̀kánjúà. 20. Nígbà tí aburú bá fọwọ́ bà á, ó máa kanra gógó. 21. Nígbà tí ọwọ́ rẹ̀ bá sì ba oore, ó máa yahun. 22. Àyàfi àwọn olùkírun, 23. àwọn tí wọ́n dúnnímọ́ ìrun wọn; 24. àwọn tó mọ ojúṣe (wọn) nínú dúkìá wọn 25. sí alágbe àti ẹni tí A ṣe arísìkí ní èèwọ̀ fún; 26. àwọn tó ń gba ọjọ́ ẹ̀san gbọ́ ní òdodo; 27. àwọn tó ń páyà ìyà Olúwa wọn, 28. dájúdájú ìyà Olúwa wọn kò ṣeé fàyàbalẹ̀ sí; 29. àwọn tó ń ṣọ́ abẹ́ wọn, 30. àyàfi lọ́dọ̀ àwọn ìyàwó wọn tàbí ẹrúbìnrin wọn ni wọn kò ti lè jẹ́ ẹni-èébú, 31. nítorí náà, ẹnikẹ́ni tó bá ń wá n̄ǹkan mìíràn lẹ́yìn ìyẹn, àwọn wọ̀nyẹn gan-an ni olùtayọ-ẹnu ààlà; 32. àwọn tó ń ṣọ́ àgbàfipamọ́ wọn àti àdéhùn wọn; 33. àwọn tó ń dúró ti ìjẹ́rìí (òdodo) wọn; 34. àti àwọn tó ń ṣọ́ àwọn ìrun wọn. 35. Àwọn wọ̀nyẹn ni alápọ̀n-ọ́nlé nínú àwọn Ọgbà Ìdẹ̀ra.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

reading-goal:continue-reading

Nota dan Renungan

reflection-not-available

Notes placeholders

Kekal Terhubung dengan Al-Quran ❤️

Peringatan ringkas yang bermakna untuk menetapkan semula, merenung dan kekal terhubung dengan al-Quran.

Baca, Dengar, Cari, dan Renungkan Al-Quran

Quran.com ialah platform dipercayai yang digunakan oleh berjuta-juta orang di seluruh dunia untuk membaca, mencari, mendengar dan merenung Al-Quran dalam pelbagai bahasa. Ia menyediakan terjemahan, tafsir, bacaan, terjemahan perkataan demi perkataan, dan alat untuk kajian yang lebih mendalam, menjadikan al-Quran boleh diakses oleh semua orang.

Sebagai Sadaqah Jariyah, Quran.com berdedikasi untuk membantu orang ramai berhubung secara mendalam dengan al-Quran. Disokong oleh Quran.Foundation , sebuah organisasi bukan untung 501(c)(3), Quran.com terus berkembang sebagai sumber percuma dan berharga untuk semua, Alhamdulillah.

Navigasi
Halaman Utama
Radio Al-Quran
Qari
Tentang Kami
Pemaju (Developers)
Kemas kini produk
Maklum balas
Bantuan
Derma
Projek Kami
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Projek tanpa untung yang dimiliki, diurus atau ditaja oleh Quran.Foundation
Pautan yang di gemari
Doa-doa daripada Al-Quran
Ayat Al-Quran Hari Ini
Ayatul Kursi
Surah Yaseen
Surah Al Mulk
Surah Ar-Rahman
Surah Al Waqi'ah
Surah Al Kahf
Surah Al Muzzammil
Peta lamanPrivasiTerma dan Syarat
© 2026 Quran.com. Hak cipta terpelihara
Sumbangan