Iniciar sesión
Iniciar sesión
Iniciar sesión
Seleccionar idioma

Ad-Dzáriyát 51:17 كانوا قليلا من الليل ما يهجعون ١٧

Página 521 · Juz 26

كَانُواْ
قَلِيلٗا
مِّنَ
ٱلَّيۡلِ
مَا
يَهۡجَعُونَ
١٧
Wọ́n máa ń sun oorun díẹ̀ nínú òru.
Continuar leyendo

Lee Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

Qualities of Those Who have Taqwa and Their Reward

Allah the Exalted informs about those who have Taqwa, that on the Day of their Return they will be amidst gardens and springs. To the contrary the miserable ones will be amidst torment, punishment, fire and chains. Allah said,

ءَاخِذِينَ مَآ ءَاتَهُمْ

…

Qualities of Those Who have Taqwa and Their Reward

Allah the Exalted informs about those who have Taqwa, that on the Day of their Return they will be a

…
Ver Tafsires

Leer en contexto

1. Allāhu fi atẹ́gùn tó ń tu erùpẹ̀ jáde nílẹ̀ ní títu-jáde tààrà búra. 2. Allāhu fi àwọn ẹ̀ṣújò tó ru òjò tó wúwo búra. 3. Allāhu fi àwọn ọkọ̀ ojú-omi tó ń rìn pẹ̀lú ìrọ̀rùn búra. 4. Allāhu fi àwọn mọlāika tó ń pín n̄ǹkan tí Ó ti pín fún ẹ̀dá búra. 5. Òdodo mà ni ohun tí À ń ṣe ní àdéhùn fún yín. 6. Àti pé dájúdájú ẹ̀san iṣẹ́ máa ṣẹlẹ̀. 7. Allāhu tún fi sánmọ̀ ọlọ́ṣọ̀ọ́ tó gún régé búra. 8. Dájúdájú ẹ̀yin wà lórí ọ̀rọ̀ tó ń takora wọn (nípa al-Ƙur’ān). 9. Ẹni tí wọ́n ń ṣẹ́ lórí kúrò níbi al-Ƙur’ān ni ẹni tí Wọ́n ti ṣẹ́ lórí kúrò níbẹ̀ (láti inú Laohul-Mahfūṭḥ). 10. Ègbé ni fún àwọn òpùrọ́; 11. àwọn tí wọ́n wà nínú àìmọ̀kan tó gbópọn tí wọ́n ti gbàgbéra. 12. tí wọ́n ń bèèrè ìgbà tí Ọjọ́ Ẹ̀san máa ṣẹlẹ̀. 13. Ní ọjọ́ náà sì ni wọn yóò máa fi Iná jẹ wọ́n níyà. 14. Ẹ tọ́ ìyà yín wò. Èyí ni n̄ǹkan tí ẹ ti ń wá pẹ̀lú ìkánjú. 15. Dájúdájú àwọn olùbẹ̀rù (Allāhu) yóò wà nínú àwọn Ọgbà Ìdẹ̀ra pẹ̀lú àwọn omi odò ìṣẹ́lẹ̀rú (ní ìsàlẹ̀ rẹ̀). 16. Wọn yóò máa gba n̄ǹkan tí Olúwa wọn bá fún wọn. Dájúdájú wọ́n ti jẹ́ olùṣe-rere ṣíwájú ìyẹn. 17. Wọ́n máa ń sun oorun díẹ̀ nínú òru. 18. Wọ́n máa ń tọrọ àforíjìn ní àfẹ̀mọ́júmọ́. 19. Nínú dúkìá wọn, wọ́n ní ojúṣe tí wọ́n ń ṣe fún alágbe àti ẹni tí A ṣe arísìkí ní èèwọ̀ fún. 20. Àwọn àmì wà ní orí ilẹ̀ fún àwọn alámọ̀dájú. 21. Nínú ẹ̀mí ara yín gan-an (àmì ìyanu wà nínú rẹ̀). Ṣé ẹ kò ríran ni? 22. Arísìkí yín àti ohun tí À ń ṣe ní àdéhùn fún yín wà nínú sánmọ̀. 23. Nítorí náà, Mó fi Olúwa sánmọ̀ àti ilẹ̀ búra, dájúdájú òdodo ni (ọ̀rọ̀ náà) gẹ́gẹ́ bí ó ṣe jẹ́ òdodo pé ẹ̀ ń fẹnu sọ̀rọ̀.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Continuar leyendo

Notas y reflexiones

No tienes ninguna nota ni reflexión sobre este versículo.

Notes placeholders

Mantente conectado al Corán ❤️

Breves recordatorios significativos para reconectar, reflexionar y mantenerse conectado con el Corán.

Lea, escuche, busque y reflexione sobre el Corán

Quran.com es una plataforma confiable utilizada por millones de personas en todo el mundo para leer, buscar, escuchar y reflexionar sobre el Corán en varios idiomas. Ofrece traducciones, tafsir, recitaciones, traducción palabra por palabra y herramientas para un estudio más profundo, haciendo que el Corán sea accesible para todos.

Como Sadaqah Jariyah, Quran.com se dedica a ayudar a las personas a conectar profundamente con el Corán. Con el apoyo de Quran.Foundation , una organización sin fines de lucro 501(c)(3), Quran.com continúa creciendo como un recurso gratuito y valioso para todos, Alhamdulillah.

Navegar
Inicio
Radio Coránica
Recitadores
Sobre nosotros
Desarrolladores
Actualizaciones de productos
Retroalimentación
Ayuda
Donar
Nuestros Proyectos
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Proyectos sin fines de lucro adquiridos, administrados o patrocinados por Quran.Foundation
Enlaces populares
Súplicas del Corán
Versículo del Corán del día
Ayatul Kursi
Yasin
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqiah
Al-Kahf
Al Muzzammil
Mapa del sitio webPrivacidadTérminos y condiciones
© 2026 Quran.com. Reservados todos los derechos
Contribuir